cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
“A ó bẹ̀rẹ̀ sí ní pín oúnjẹ tótó ẹgbẹ̀rún méjìlélógójì tọ́ọ̀nù, èyí tí Ààrẹ Tinúbú ti buwọ̀lú, káàkiri ìpínlẹ̀ mẹ́rìndíngi ní ọ̀sẹ̀ yìí.".
bbc
yo
“A ó bẹ̀rẹ̀ sí ní pín oúnjẹ tótó ẹgbẹ̀rún méjìlélógójì tọ́ọ̀nù, èyí tí ààrẹ Tinúbú ti buwọ̀lú, káàkiri ìpínlẹ̀ mẹ́rìndíngi ní ọ̀sẹ̀ yìí.” This article contains content provided by Twitter.
bbc
yo
wé ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cooDiutarónómì and other Techologies.
bbc
yo
You May want to read Twitter Cookie policy and ẹṣin policy before 69pting.
bbc
yo
“A ó bẹ̀rẹ̀ sí ní pín oúnjẹ tótó ẹgbẹrun mejilelogoji tọ, èyí tí àárẹ̀ Tinúbú ti buwọ̀lú, káàkiri ìpínlẹ̀ mẹ́rìndíndín ní ọ̀sẹ̀ yìí.” This article contains content provided by Twitter.
bbc
yo
End of Twitter Post content is not available minisita naa sọ pé ìjọba ń ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú Àjọ Tó Ń mójútó Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàjáwìrì, Nema, àti àwọn ẹ̀so alábò dṣs láti rí pé àwọn oúnjẹ yìí dé sí ọ̀dọ̀ àwọn aráàlú tó nílò rẹ̀..
bbc
yo
End of Twitter Post content is not available minisita naa sọ pé ìjọba ń ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú Àjọ Tó Ń mójútó Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàjáwìrì, Nema, àti àwọn ẹ̀so alábò dṣs láti ri pé àwọn oúnjẹ yìí dé sí ọ̀dọ̀ àwọn aráàlú tó nílò rẹ̀.
bbc
yo
Bákan náà ló kéde pé tọ́ọ̀nù ìrẹsì méjìdínlọ́gọ́ta ni àwọn fi ránṣẹ́ sí àwọn ọjà káàkiri..
bbc
yo
Bákan náà ló kéde pé tọ́ọ̀nù ìrẹsì méjìdínlọ́gọ́ta ni àwọn fi ránṣẹ́ sí àwọn ọjà káàkiri.
bbc
yo
ọ̀pọ̀ ọmọ Nàíjíríà ló ti sún kan ògiri báyìí látàrí ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ tó gbòde..
bbc
yo
content is not available minisita naa so pe ijoba n sise po pelu ajo to n mojuto iṣẹlẹ pajawiri, nema, ati awon eso alabo DSs lati ri pe awon ounje yii de si ọdọ awon aráàlú to nilo re.
bbc
yo
ọ̀pọ̀ ọmọ Nàíjíríà ló ti sún kan ògiri báyìí látàrí ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ tó gbòde.
bbc
yo
Ìròyìn ní nǹkan bíi ìdajì aráàlú ló ń gbé ninu ìṣẹ́ ati òṣì nítorí bí wọn kò ṣe rí oúnjẹ ìgbà mẹta jẹ lojumọ..
bbc
yo
Mínísítà náà sọ pé ìjọba ń ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú àjọ tó ń jásí ìṣẹ̀lẹ̀ jájámọ́, Néma, àti àwọn èso alín dṣs láti rí pé àwọn ó yìí dé sí ọ̀dọ̀ àwọn ìṣènà tó nílò rẹ̀.
bbc
yo
Ìròyìn ní nǹkan bíi ìdajì aráàlú ló ń gbé ninu ìṣẹ́ ati òṣì nítorí bí wọn kò ṣe rí oúnjẹ ìgbà mẹta jẹ lojumọ.
bbc
yo
Gbogbo rògbòdìyàn náà kò sẹ̀yìn ìgbésẹ̀ ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí owó ìrànwọ́ orí epo bẹntiro àti bó ṣe já agbára owó náírà sílẹ̀..
bbc
yo
Gbogbo rògbòdìyàn náà kò sẹ̀yìn ìgbésẹ̀ ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí owó ìrànwọ́ orí epo bẹntiro àti bó ṣe já agbára owó náírà sílẹ̀.
bbc
yo
Èyí tí ń mú kí ara kan ọ̀pọ̀ aráàlú, tí àwọn míì sì ń lọ fọ́ ibùdó tí ìjọba ń kó oúnjẹ pamọ́ sí kí wọ́n lè bọ́ ara wọn àtàwọn mọ̀lẹ́bí wọn..
bbc
yo
Èyí ti ń mú kí ara kan ọ̀pọ̀ aráàlú, tí àwọn míì sì ń lọ fọ́ ibùdó tí ìjọba ń kó oúnjẹ pamọ́ sí kí wọ́n lè bọ́ ara wọn àtàwọn mọ̀lẹ́bí wọn.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images ọwọ́ ọlọ́pàá ti tẹ èèyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dógún tó lọ́wọ́ nínú bí àwọn èèyàn kan ṣe fọ ilé oúnjẹ kan l'Abuja, tí wọ́n sì kó àwọn oúnjẹ náà lọ.
bbc
yo
Ọjọ́ Àìkú, ọjọ́ kẹta, oṣù kẹta, ọdún 2024, ni ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé.
bbc
yo
Ọ̀sán ọjọ́ àìkú ni fídíò kan gba orí ayélujára, èyí tó ṣàfihàn bí ẹ̀ẹ́ro rẹpẹtẹ ṣe ya wọ ilé kan tí wọ́n kó oúnjẹ pamọ́ sí.
bbc
yo
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àbùjá ni ilé oúnjẹ náà wà, a gbọ́ pé àwọn èèyàn tún ya wá láti àwọn ìlú tó súnmọ́ agbègbè náà, wọ́n sì kó oúnjẹ lápòlápò lọ..
bbc
yo
Ọwọ́ ọlọ́pàá ti tẹ èèyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dógún tó lọ́wọ́ nínú bí àwọn èèyàn kan ṣe fọ ilé oúnjẹ kan l’abuja, tí wọ́n sì kó àwọn oúnjẹ náà lọ.
bbc
yo
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àbùjá ni ilé oúnjẹ náà wà, a gbọ́ pé àwọn èèyàn tún ya wá láti àwọn ìlú tó súnmọ́ agbègbè náà, wọ́n sì kó oúnjẹ lápòlápò lọ.
bbc
yo
Ṣáájú ni ìròyìn sọ pé Àjọ Tó Ń mójútó Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàjáwìrì ní Nàìjíríà, National Emergency Management Agency, Nema, ló ni ibùdó náà..
bbc
yo
Ṣáájú ni ìròyìn sọ pé Àjọ Tó Ń mójútó Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàjáwìrì ní Nàìjíríà, National Emergency Management Agency, Nema, ló ni ibùdó náà.
bbc
yo
Ṣugbọn ninu ìkéde kan tó fi síta, Àjọ Nema sọ pé ilé ìkẹ́rùsí náà kìí ṣe ti òun..
bbc
yo
Ṣugbọn ninu ìkéde kan tó fi síta, àjọ nemá sọ pé ilé ìkẹ́rùsí náà kìí ṣe ti òun.
bbc
yo
Agbẹnusọ àjọ náà, Manzo Ezekiel, nínú àtẹ̀jáde kan tó fi lédè fún àwọn akọ̀ròyìn fi di rẹ̀ múlẹ̀ pé ìṣẹ̀lẹ̀ náà tó wáyé lọ́jọ́ àìkú, ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 2024 kò ní nǹkan ṣe pẹ̀lú àjọ Nema ṣùgbọ́n àwọn bá àjọ tó ní ilé oúnjẹ kẹ́dùn lórí ohun tó wáyé..
bbc
yo
Agbẹnusọ àjọ náà, manzo Ezekiel, nínú àtẹ̀jáde kan tó fi lédè fún àwọn akọ̀ròyìn fi di rẹ̀ múlẹ̀ pé ìṣẹ̀lẹ̀ náà tó wáyé lọ́jọ́ àìkú, ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 2024 kò ní nǹkan ṣe pẹ̀lú àjọ nẹ́ma ṣùgbọ́n àwọn bá àjọ tó ní ilé oúnjẹ kẹ́dùn lórí ohun tó wáyé.
bbc
yo
Ìròyìn sọ pé ilé ìkẹ́rùsí náà, ló jẹ́ ti Ẹ̀ka Ìjọba ìlú Àbújá, tó ń mójútó ìdàgbàsókè iṣẹ́ àgbẹ̀, ló ni ibùdó náà..
bbc
yo
Ìròyìn sọ pé ilé ìkẹ́rùsí náà, ló jẹ́ ti Ẹ̀ka Ìjọba ìlú Àbújá, tó ń mójútó ìdàgbàsókè iṣẹ́ àgbẹ̀, ló ní ibùdó náà.
bbc
yo
Agbẹnusọ ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn náà, kariy Aliyu fi di ìṣẹ̀lẹ̀ náà múlẹ̀ pé ilẹ̀ oúnjẹ tó jẹ́ ti ẹ̀ka náà ni àwọn aráàlú ya wò, tí wọ́n sì gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ lọ..
bbc
yo
Agbẹnusọ ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn náà, kari· Aliyu fi di ìṣẹ̀lẹ̀ náà múlẹ̀ pé ilẹ̀ oúnjẹ tó jẹ́ ti ẹ̀ka náà ni àwọn aráàlú ya wò, tí wọ́n sì gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ lọ.
bbc
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló mú káwọn èèyàn máa sọ pé ẹbí tó wà nílùú, àti ìyàn tó ń mú ló fà á táwọn aráàlú fi fọ ibẹ̀ tí wọ́n kó oúnjẹ lọ..
bbc
yo
Agbẹnusọ ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn náà, kariy Aliyu fi di ìṣẹ̀lẹ̀ náà múlẹ̀ pé ilẹ̀ oúnjẹ tó jẹ́ ti ẹ̀ka náà ni àwọn aráàlú ya wò, tí wọ́n sì gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ lọ.
bbc
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló mú káwọn èèyàn máa sọ pé ẹbí tó wà nílùú, àti ìyàn tó ń mú ló fà á táwọn aráàlú fi fọ ibẹ̀ tí wọ́n kó oúnjẹ lọ.
bbc
yo
ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ àti ọjà tí ń bá àwọn èèyàn fínra ní Nàìjíríà láti ìgbà tí ìjọba Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú ti yọ owó ìrànwọ́ orí epo, ṣùgbọ́n ó tún burú sí i láti oṣù kinni, ọdún 2024..
bbc
yo
ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ àti ọjà tí ń bá àwọn èèyàn fínra ní Nàìjíríà láti ìgbà tí ìjọba Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú ti yọ owó ìrànwọ́ orí epo, ṣùgbọ́n ó tún burú sí i láti oṣù kinni, ọdún 2024.
bbc
yo
Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá sọ fún iléeṣẹ́ ìròyìn Channels TV pé, gbogbo àṣírí tó wà nídìí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló hàn síléeṣẹ́ ọlọ́pàá, báwọn kan ṣe fọ ẹka oúnjẹ nílẹ̀ ìkẹ́rù sí tó wà ní Tasha, l'Abuja..
bbc
yo
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá sọ fún iléeṣẹ́ ìròyìn Channels TV pé, gbogbo àṣírí tó wà nídìí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló hàn síléeṣẹ́ ọlọ́pàá, báwọn kan ṣe fọ ẹka oúnjẹ nílẹ̀ ìkẹ́rù sí tó wà ní Tasha, l'Abuja.
bbc
yo
''A rí i bí wọ́n ṣe ba ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan jẹ́ níbẹ̀, a sì ti kápá gbogbo wàhálà náà.
bbc
yo
''Èèyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dógún tó jẹ afurasi ni a ti mu, méjì nínú wọn jẹ́ ọlọ́dẹ tó ń ṣọ́ ilé oúnjẹ náà.’
bbc
yo
''Èèyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dógún tó jẹ afurasi ni a ti mu, méjì nínú wọn jẹ́ olóde tó ń ṣọ́ ilé oúnjẹ náà.’ Àpò àgbàdo mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (26), ọ̀kadà márùn-ún àti àwọn nǹkan táwọn èèyàn náà bàjẹ́ ni wọ́n rí gbà lọ́wọ́ wọn bí wọ́n ṣe sọ..
bbc
yo
''Èèyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dógún tó jẹ afurasi ni a ti mu, méjì nínú wọn jẹ́ olóde tó ń ṣọ́ ilé oúnjẹ náà.’ Àpò àgbàdo mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (26), ọ̀kadà márùn-ún àti àwọn nǹkan táwọn èèyàn náà bàjẹ́ ni wọ́n rí gbà lọ́wọ́ wọn bí wọ́n ṣe sọ.
bbc
yo
Láti ìgbà tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé ni àjọ Nema ti kó àwọn òṣìṣẹ́ aláàbò láti dáàbò bo àwọn ilé oúnjẹ káàkiri orílẹ̀èdè Nàìjíríà..
bbc
yo
Láti ìgbà tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé ni àjọ Nema ti kó àwọn òṣìṣẹ́ aláàbò láti dáàbò bo àwọn ilé oúnjẹ káàkiri orílẹ̀èdè Nàìjíríà.
bbc
yo
Ọ̀gá àgbà fún àjọ náà ló gbé àṣẹ náà kalẹ̀ fún àwọn ẹ̀ka nemá káàkiri Nàìjíríà ..
bbc
yo
’’èèyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dógún tó jẹ afurasi ni a ti mu, méjì nínú wọn jẹ olóde tó ń ṣọ́ ilé oúnjẹ náà.’ Àpò àgbàdo mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (26), ọ̀kadà márùn-ún àti àwọn nǹkan táwọn èèyàn náà bàjẹ́ ni wọ́n rí gbà lọ́wọ́ wọn bí wọ́n ṣe sọ.
bbc
yo
Ọ̀gá àgbà fún àjọ náà ló gbé àṣẹ náà kalẹ̀ fún àwọn ẹka nemá káàkiri Nàìjíríà .
bbc
yo
“Láti le má fi ayé sílẹ̀ fún yíyáwó ilé oúnjẹ nemà, ògá àgbà àjọ náà, Mustapha Habib Ahmed ti paláṣẹ fún gbogbo ọ̀gá ẹ̀ka nemá káàkiri láti fikùn ìdãbò sí àwọn ilé oúnjẹ àti káàkiri iléeṣẹ́ nemá káàkiri orílẹ̀èdè Nàìjíríà.".
bbc
yo
Àpò àgbàdo mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (26), ọ̀kadà márùn-ún àti àwọn nǹkan táwọn èèyàn náà bàjẹ́ ni wọ́n rí gbà lọ́wọ́ wọn bí wọ́n ṣe sọ.
bbc
yo
“Láti le má fi ayé sílẹ̀ fún yíyáwó ilé oúnjẹ nemá, ọ̀gá àgbà àjọ náà, Mustapha Habib Ahmed ti paláṣẹ fún gbogbo ọ̀gá ẹ̀ka nemá káàkiri láti fikùn ìdãbò sí àwọn ilé oúnjẹ àti káàkiri iléeṣẹ́ nemá káàkiri orílẹ̀èdè Nàìjíríà.” This article contains content provided by Twitter.
bbc
yo
End of Twitter Post content is not available © 2024 BBC.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Bọ́lá Tinúbú/BBC ìjọba Orílẹ̀èdè Nàìjíríà ti gbé àwọn àmúyẹ tí aráàlú gbọdọ̀ ní, kó tó di pé wọ́n lè jẹ́ àǹfààní owó ìrànwọ́ ẹgbẹ̀rún márùndínlọ́gbọ̀n (₦25,000) náírà tí wọ́n fẹ́ẹ́ gbé síta.
bbc
yo
Owó náà ni ìjọba sọ pé ìdílé mẹ́ẹ̀dógún ni yóò jẹ́ àǹfààní yìí, àti pé wọ́n gbọdọ̀ ní àwọn àmúyẹ tó bá ìlànà tí wọ́n kà sílẹ̀ mu, bí ìgbé ayé ìrọ̀rùn ṣe ń le koko.
bbc
yo
Bí àwọn aráàlú ṣe ń pariwo pé ìlú kò fararọ, àárẹ̀ Bọ́lá Tinúbú ti sọ pé niṣẹ́ ni wọn yóò bẹ̀rẹ̀ síí fi àwọn owó náà ránṣẹ́ sínú àpò ilé ìfowópamọ́ àwọn aláìní àti àwọn tó kù díẹ̀ kátó fún.
bbc
yo
Kó tó di pé wọ́n dá àwọn ètò owó ìrànwọ́ tó wà níta tẹ́lẹ̀ dúró, ọmọ Nàìjíríà tí kò dín ní mílíọ̀nù mẹ́ta ni wọ́n ti ń jẹ àǹfààní náà..
bbc
yo
Ìjọba orílẹ̀èdè Nàìjíríà ti gbé àwọn àmúyẹ tí aráàlú gbọdọ̀ ní, kó tó di pé wọ́n lè jẹ àǹfààní owó ìrànwọ́ ẹgbẹ̀rún márùndínlọ́gbọ̀n (₦25,000) náírà tí wọ́n fẹ́ẹ́ gbé síta.
bbc
yo
Kó tó di pé wọ́n dá àwọn ètò owó ìrànwọ́ tó wà níta tẹ́lẹ̀ dúró, ọmọ Nàìjíríà tí kò dín ní mílíọ̀nù mẹ́ta ni wọ́n ti ń jẹ àǹfààní náà.
bbc
yo
Ṣùgbọ́n nítorí àwọn nǹkan tí kò fararọ nílùú, ìjọba ní láti kéde ìdádúró àwọn ètò ìrànwọ́ náà, síbẹ̀ ìjọba ni àwọn fẹ́ẹ́ lé àlékún àwọn tó ń jẹ àǹfààní yìí sí ìdílé mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀dógún..
bbc
yo
Ṣùgbọ́n nítorí àwọn nǹkan tí kò fararọ nílùú, ìjọba ní láti kéde ìdádúró àwọn ètò ìrànwọ́ náà, síbẹ̀ ìjọba ni àwọn fẹ́ẹ́ lé àlékún àwọn tó ń jẹ àǹfààní yìí sí ìdílé mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀dógún.
bbc
yo
Mínísítà fọ̀rọ̀ ètò ìṣúná àti Alákòso Mínísítà fọ̀rọ̀ ètò ọrọ̀ Ajé, Wálé Ẹdun nínú ìfọ̀rọ̀wérọ̀ tó ṣe láìpẹ́ yìí pẹ̀lú iléeṣẹ́ amóhùnmáwòrán Channels jẹ́ kó di mímọ̀ pé aráàlú tó bá fẹ́ẹ́ jẹ àńfààní gbọ́dọ̀ ní nọ́ḿbà ìdánimọ̀ àpapọ̀ tí a mọ̀ sí National identiNígbà Number (nín)..
bbc
yo
Mínísítà fọ̀rọ̀ ètò ìṣúná àti Alákòso Mínísítà fọ̀rọ̀ ètò ọrọ̀ Ajé, Wálé Ẹ̀dùn nínú ìfọ̀rọ̀wérọ̀ tó ṣe láìpẹ́ yìí pẹ̀lú Iléeṣẹ́ amóhùnmáwòrán jẹ́ kó kò di mímọ̀ pé gbígbé tó bá fẹ́ẹ̀ jẹ́ ànfààní gbọ́dọ̀ ní nọ́bà Ìpapọ̀ Àpapọ̀ tí a mọ̀ sí National identidọ́gba Nudọ́gba (nínẹ̀ (nin).
bbc
yo
Lára àwọn àmúyẹ míràn tó tún mẹ́nuba ni pé àwọn tó bá máa jẹ àǹfààní yóò tún ní nọ́mbà ìdánimọ̀ ilé ìfowópamọ́, ìyẹn biOmeriatric Vetrification Number (BV) àti fóònù káwù..
bbc
yo
Lára àwọn àmúyẹ míràn tó tún mẹ́nuba ni pé àwọn tó bá máa jẹ àǹfààní yóò tún ní nọ́mbà ìdánimọ̀ ilé ìfowópamọ́, ìyẹn biOmeriatric Vetrification Number (BV) àti fóònù alágbéká.
bbc
yo
Ẹ̀dùn ni èyí ní láti ríi pé ọwọ́ náà dé ọ̀dọ̀ àwọn tí ìjọba ní lẹ́ròǹgbà, kí màgòmágó má sì lọ wọnú ètò ohun..
bbc
yo
Ẹ̀dùn ni èyí ní láti ríi pé ọwọ́ náà dé ọ̀dọ̀ àwọn tí ìjọba ní lẹ́ròǹgbà, kí màgòmágó má sì lọ wọnú ètò ohun.
bbc
yo
Ó tẹ̀síwájú pé àpapọ̀ owó tí ìdílé kọ̀ọ̀kan yóo gbà jẹ́ ẹgbẹrun marundinlọgọrin (ń75,000) naira..
bbc
yo
Ó tẹ̀síwájú pé àpapọ̀ owó tí ìdílé kọ̀ọ̀kan yóo gbà jẹ́ ẹgbẹrun marundinlọgọrin (ń75,000) naira.
bbc
yo
“Ẹgbẹ̀rún márùndínlọ́gbọ̀n ni ìdílé kọ̀ọ̀kan yóò gbà láàrín oṣù kan, ìdílé kan sì gbọdọ̀ ní èèyàn márùn-ún, kí ètò náà le kárí fún oṣù mẹ́ta.
bbc
yo
Ìdílé mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀dógún ni yóò gba owó yìí fún oṣù mẹ́ta, èyí tí àpapọ̀ rẹ̀ jẹ́ ìdílé márùndínlọ́gọ́rin.".
bbc
yo
Ìdílé mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀dógún ni yóò gba owó yìí fún oṣù mẹ́ta, èyí tí àpapọ̀ rẹ̀ jẹ́ ìdílé márùndínlọ́gọ́rin.” Yàtọ̀ sí èyí, mínísítà fọ̀rọ̀ ètò ìṣúná tún ṣàlàyé síwájú pé ìjọba tún fẹ́ẹ́ ṣe ìrànwọ́ fáwọn oníṣẹ́ òwò, oníṣòwò, ọ̀dọ́, olókoòwò kékèèké, àwọn obìnrin àti àwọn oní wóróbo..
bbc
yo
Ìdílé mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀dógún ni yóò gba owó yìí fún oṣù mẹ́ta, èyí tí àpapọ̀ rẹ̀ jẹ́ ìdílé márùndínlọ́gọ́rin.” Yàtọ̀ sí èyí, mínísítà fọ̀rọ̀ ètò ìṣúná tún ṣàlàyé síwájú pé ìjọba tún fẹ́ẹ́ ṣe ìrànwọ́ fáwọn oníṣẹ́ òwò, oníṣòwò, ọ̀dọ́, olókoòwò kékèèké, àwọn obìnrin àti àwọn oní wóróbo.
bbc
yo
Ó ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta (₦50,000) naira ni àwọn wọ̀nyí yóò gbà gẹ́gẹ́ bí owó ìrànwọ́ tí wọ́n kò sì ní dá a padà..
bbc
yo
Ó ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta (₦50,000) naira ni àwọn wọ̀nyí yóò gbà gẹ́gẹ́ bí owó ìrànwọ́ tí wọ́n kò sì ní dá a padà.
bbc
yo
Síbẹ̀, ìlànà ìgbàlódé ni wọ́n yóò fi ṣe àkọsílẹ̀ àwọn tí yóò jẹ àǹfààní, tó fi jẹ́ pé èèyàn tí kò dín ní ẹgbẹ̀rún kan ló máa láǹfààní ní ìjọba ìbílẹ̀ ìrínijẹ tó wà káàkiri Nàìjíríà..
bbc
yo
Síbẹ̀, ìlànà ìgbàlódé ni wọ́n yóò fi ṣe àkọsílẹ̀ àwọn tí yóò jẹ àǹfààní, tó fi jẹ́ pé èèyàn tí kò dín ní ẹgbẹ̀rún kan ló máa láǹfààní ní ìjọba ìbílẹ̀ ìrínijẹ tó wà káàkiri Nàìjíríà.
bbc
yo
Yàtò sí èyí, mínísítà fọ̀rọ̀ ètò ìṣúná tún ṣàlàyé síwájú pé ìjọba tún fẹ́ẹ́ ṣe ìrànwọ́ fáwọn oníṣẹ́ òwò, oníṣòwò, odò, olóko kékèèké, àwọn obìnrin àti àwọn oní wóróbo.
bbc
yo
Ẹ̀dùn ni ọ̀nà tó dára lèyí láti fi ṣe ìrànwọ́ farar lásìkò yìí..
bbc
yo
Ẹ̀dùn ni ọ̀nà tó dára lèyí láti fi ṣe ìrànwọ́ fararilé lásìkò yìí.
bbc
yo
Orísun àwòrán, oúnjẹ/Olùtti Images láìpẹ́ yìí ni Ìjọba Àpapọ̀ Orílẹ̀èdè Nàìjíríà kéde àwọn ọ̀nà àbáyọ mẹ́ta tí yóò mú àdínkù bá ìṣòro tí àwọn aráàlú ń kojú lásìkò yìí.
bbc
yo
Lára àwọn ọ̀nà àbáyọ àkọ́kọ́ ni pínpín oúnjẹ Tirela ńlá ẹgbẹ̀rún méjìlélógójì (42,000n) láti inú ilé ikọ̀ oúnjẹ pamọ́ sí ti iléeṣẹ́ tó ń rí sọ̀rọ̀ iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn, èyí tí yóò mú ìgbé ayé dẹrùn fún aráàlú.
bbc
yo
Lẹ́yìn èyí ni ìjọba tún sọ pé àwọn yóò bá àwọn iléeṣẹ́ tó ń ṣe ìrẹsì káàkiri Nàìjíríà sọ̀rọ̀ láti sọ àsọyépọ̀ nípa pípèsè ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́ta làla (60,000n) ìrẹsì láti tà káàkiri orílẹ̀èdè yìí.
bbc
yo
Ìgbésẹ̀ Ẹlẹ́ẹ̀kẹta ni láti bẹ̀rẹ̀ síí kó oúnjẹ wọlé sí Nàìjíríà láti ilẹ̀ òkèèrè, èyí tí yóò mú ìdẹ̀rùn bá ìgbáyégbádùn aráàlú..
bbc
yo
Láìpẹ́ yìí ni ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀èdè Nàìjíríà kéde àwọn ọ̀nà àbáyọ mẹ́ta tí yóò mú àdínkù bá ìṣòro tí àwọn aráàlú ń kojú lásìkò yìí.
bbc
yo
Ìgbésẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta ni láti bẹ̀rẹ̀ síí kó oúnjẹ wọlé sí Nàìjíríà láti ilẹ̀ òkèèrè, èyí tí yóò mú ìdẹ̀rùn bá ìgbáyégbádùn aráàlú.
bbc
yo
Ǹjẹ́ ẹ wá mọ ohun tí àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí túnmọ̀ sí? Ipa wo ni wọ́n yóò kó? Àti pé báwo ni yóò ṣe mú àyípadà rere bá ìgbé ayé ìnira tí àwọn èèyàn ń là kọjá? .
bbc
yo
Ǹjẹ́ ẹ wá mọ ohun tí àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí túnmọ̀ sí? Ipa wo ni wọ́n yóò kó? Àti pé báwo ni yóò ṣe mú àyípadà rere bá ìgbé ayé ìnira tí àwọn èèyàn ń là kọjá? Onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé àti ìpèsè oúnjẹ nnì, ọ̀mọ̀wé Muhammed Suleman kani, ẹni tó tún jẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Federal Government College of Education tó wà nípìnlẹ̀ Kano sọ pé ìgbésẹ̀ gidi ni ìjọba àpapọ̀ gbé, nítorí pé yóò mú ìdẹ̀rùn bá ìlàkàkà aráàlú..
bbc
yo
Ǹjẹ́ ẹ wá mọ ohun tí àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí túnmọ̀ sí? Ipa wo ni wọ́n yóò kó? Àti pé báwo ni yóò ṣe mú àyípadà rere bá ìgbé ayé ìnira tí àwọn èèyàn ń là kọjá? Onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé àti ìpèsè oúnjẹ nnì, ọ̀mọ̀wé Muhammed Suleman kani, ẹni tó tún jẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Federal Government College of Education tó wà nípìnlẹ̀ Kano sọ pé ìgbésẹ̀ gidi ni ìjọba àpapọ̀ gbé, nítorí pé yóò mú ìdẹ̀rùn bá ìlàkàkà aráàlú.
bbc
yo
Ó ní láwọn ìgbà tí orílẹ̀èdè bá ń kojú irúfẹ́ àwọn ìṣòro báyìí, ohun tó kan ni láti wá ọ̀nà àbáyọ tí yóò mú ìrọ̀rùn bá aráàlú..
bbc
yo
Ó ní láwọn ìgbà tí orílẹ̀èdè bá ń kojú irúfẹ́ àwọn ìṣòro báyìí, ohun tó kàn ni láti wá ọ̀nà àbáyọ tí yóò mú ìrọ̀rùn bá aráàlú.
bbc
yo
Ṣùgbọ́n ó ní àwọn oúnjẹ ti ìjọba àpapọ̀ ń sọ wọ̀nyí “Kìí ṣe èyí tí wọn yóò kó sílẹ̀ fún ọmọ Nàìjíríà lọ́fẹ̀ẹ́.".
bbc
yo
Ṣugbọn ó ní àwọn oúnjẹ tí ìjọba àpapọ̀ ń sọ wọnyi “Kìí ṣe èyí tí wọn yóo kó sílẹ̀ fún ọmọ Nàìjíríà lọ́fẹ̀ẹ́.” Ó ní ohun tí ìjọba yóo ṣe ni pé, wọ́n máa dínwó àwọn oúnjẹ náà, bí àpẹẹrẹ tí oúnjẹ kan bá jẹ́ ẹgbẹrun mẹ́wàá, ìjọba yóo tà á ní ẹgbẹrun meje tabi ẹgbẹrun mẹjọ..
bbc
yo
Onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé àti ìpèsè oúnjẹ nnì, ọ̀mọ̀wé Muhammed Suleman kani, ẹni tó tún jẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Federal Government College of Education tó wà nípìn Kano sọ pé ìgbésẹ̀ gidi ni ìjọba àpapọ̀ gbé, nítorí pé yóò mú ìdẹ̀rùn bá ìlàkàkà aráàlú.
bbc
yo
Ṣugbọn ó ní àwọn oúnjẹ tí ìjọba àpapọ̀ ń ṣọ́ wọnyi “Kìí ṣe èyí tí wọn yóo kó sílẹ̀ fún ọmọ Nàìjíríà lọ́fẹ̀ẹ́.” Ó ní ohun tí ìjọba yóo ṣe ni pé, wọ́n máa dínwó àwọn oúnjẹ náà, bí àpẹẹrẹ tí oúnjẹ kan bá jẹ́ ẹgbẹrun mẹ́wàá, ìjọba yóo tà á ní ẹgbẹrun meje tabi ẹgbẹrun mẹjọ.
bbc
yo
Kẹ́ni sọ pé “Ìjọba ti gbé ìrànwọ́ dìde lórí àwọn oúnjẹ lórílẹ̀èdè Nàìjíríà.".
bbc
yo
Kẹ́ni sọ pé “Ìjọba ti gbé ìrànwọ́ dìde lórí àwọn oúnjẹ lórílẹ̀èdè Nàìjíríà.” Ó ní ìgbésẹ̀ yóò ran àwọn èèyàn tí wọ́n ríi pé owó oṣù òṣìṣẹ́ kò yí padà pẹ̀lú bí ètò ọrọ̀ ajé ṣe rí lọ́wọ́, àti pé àwọn oníṣòwò náà ń kojú àìta ọjà wọn nítorí pé agbára káká làwọn èèyàn fi ń rí owó láti wọ inú ọjà..
bbc
yo
Kẹ́ni sọ pé “Ìjọba ti gbé ìrànwọ́ dìde lórí àwọn oúnjẹ lórílẹ̀èdè Nàìjíríà.” Ó ní ìgbésẹ̀ yóò ran àwọn èèyàn tí wọ́n ríi pé owó oṣù òṣìṣẹ́ kò yí padà pẹ̀lú bí ètò ọrọ̀ ajé ṣe rí lọ́wọ́, àti pé àwọn oníṣòwò náà ń kojú àìta ọjà wọn nítorí pé agbára káká làwọn èèyàn fi ń rí owó láti wọ inú ọjà.
bbc
yo