cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Iwadi to waye laipẹ kan daba pe awọn iṣẹlẹ El Niño n fa idinku idagbasoke eto-ọrọ agbaye ni pataki, ipa kan eyiti o le pọ si ni ọjọ iwaju.
bbc
yo
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ El Niño àti la níná máa ń wáyé ní gbogbo ọdún méjì sí méje, tó sì lò tó oṣù mẹ́sàn án sí méjìlá..
bbc
yo
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ El Niño àti la níná máa ń wáyé ní gbogbo ọdún méjì sí méje, tó sì lò tó oṣù mẹ́sàn án sí méjìlá.
bbc
yo
Wọn kò ṣe arọ́pò dandan: àwọn ìsẹ̀lẹ̀ la níná kò wọ́pọ̀ tó ti àwọn ìsẹ̀lẹ̀ el Niño..
bbc
yo
Àwọn ọ̀gbẹlẹ̀ àti omíyalé tí ó ṣẹlẹ̀ nípasẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ El Niño ti ọdún 2015–2016 ṣàkóbá sí ààbò oúnjẹ fún ọ lé ní ọgọ́ta mílíọ̀nù ènìyàn, ní ìbámu sí Àjọ oúnjẹ àti Ọ̀gbìn ti ún.
bbc
yo
Wọn kò ṣe arọ́pò dandan: àwọn ìsẹ̀lẹ̀ la níná kò wọ́pọ̀ tó ti àwọn ìsẹ̀lẹ̀ el ọ̀árámù.
bbc
yo
Orísun àwòrán, ẹ̀pà ni ọdún 2021, àwọn onímọ̀-jinlẹ̀ ojú-ọjọ́ un ti un, IPCC, sọ pé àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ Ẹgbẹ̀ èyítí ó ti wáyé ní ọdún 1950 lágbára ju èyítí a ṣe àkíyèsí láàrin ọdún 1850 àti 1950..
bbc
yo
Orísun àwòrán, ẹ̀pà ni ọdún 2021, àwọn onímọ̀-jinlẹ̀ ojú-ọjọ́ un ti un, IPCC, sọ pé àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ Ẹsọsọ èyítí ó ti wáyé ní ọdún 1950 lágbára ju èyítí a ṣe àkíyèsí láàrín ọdún 1850 àti 1950.
bbc
yo
Ṣugbọn o tún sọ pé àwọn òrùka igi ati àwọn ẹ̀rí ìtàn mìíràn fihàn pé àwọn ìyàtọ̀ ti wà ninu ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati agbára ti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọnyi láti àwọn ọdún 1400..
bbc
yo
Ṣugbọn o tún sọ pé àwọn òrùka igi ati àwọn ẹ̀rí ìtàn mìíràn fihàn pé àwọn ìyàtọ̀ ti wà ninu ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati agbára ti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọnyi láti àwọn ọdún 1400.
bbc
yo
IPCC parí pé kò sí ẹ̀rí tí ó dájú pé ìyípadà ojú-ọjọ́ ti ní ipa lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí..
bbc
yo
IPCC pari pé kò sí ẹ̀rí tí ó dájú pé ìyípadà ojú-ọjọ́ ti ní ipa lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí.
bbc
yo
Diẹ ninu awọn awoṣe oju-ọjọ daba pe awọn iṣẹlẹ El Niño yoo di loorekoore ati siwaju sii bi abajade ti ImọRrúsì agbaye - o le mu awọn iwọn otutu pọ si siwaju - ṣugbọn eyi ko daju..
bbc
yo
Ní ọdún 2021, àwọn onímọ̀-jinlẹ̀ ojú-ọjọ́ un ti ún, IPCC, sọ pé àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ Ẹsọsọ èyítí ó ti wáyé ní ọdún 1950 lágbára ju èyítí a ṣe àkíyèsí láàrín ọdún 1850 àti 1950.
bbc
yo
Diẹ ninu awọn awoṣe oju-ọjọ daba pe awọn iṣẹlẹ El Niño yoo di loorekoore ati siwaju sii bi abajade ti ImọRrúsì agbaye - o le mu awọn iwọn otutu pọ si siwaju - ṣugbọn eyi ko daju.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images Yorùbá bọ́ wọn ni ebi kìí wọnú kí ọ̀rọ̀ míì wọ̀ ọ́.
bbc
yo
Ọ̀rọ̀ ọ̀wọ́n gogò tó gbòde ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà kan ara ilẹ̀ kan ara oko Èyí ló mú àwọn àgbẹ̀ ní ẹkùn ìwọ̀-oòrùn ní orílẹ̀ èdè yìí ṣe gbé ìpàdé àpérò kan idẹ láti wá ojútùú sọ́rọ̀ ẹbí tó gbòde kan lásìkò yìí.
bbc
yo
Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ níbi ìpàdé náà, ìga ẹgbẹ́ àwọn agbe ní agbègbè ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà, Ọmọba, Segun Ksa kó gbogbo àwọn àó láti padà sí oko, kí Ìpèsè óbí ń pọ̀ yanturu..
bbc
yo
Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ níbi ìpàdé náà, ìga ẹgbẹ́ àwọn agbe ní agbègbè ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà, Ọmọba, Segun Ksa kó gbogbo àwọn àó láti padà sí oko, kí Ìpèsè óso ń pọ̀ yanturu.
bbc
yo
Ó ní tí ebi bá ti kúrò nínú ìṣẹ́, iṣẹ́ bùṣe àti pé bí Nàìjíríà kò ṣe máa pèsè oúnjẹ tó tó ṣe àmúlò fún àwọn ènìyàn rẹ̀ ló fà bí oúnjẹ ṣe ń gbówó lórí ní gbogbo ìgbà..
bbc
yo
Ó ní tí ebi bá ti kúrò nínú ìṣẹ́, iṣẹ́ bùṣe àti pé bí Nàìjíríà kò ṣe máa pèsè oúnjẹ tó tó ṣe àmúlò fún àwọn ènìyàn rẹ̀ ló fà bí oúnjẹ ṣe ń gbówó lórí ní gbogbo ìgbà.
bbc
yo
Dàṣàolu ni lóòótọ́ ni pé ọ̀rọ̀ ààbò ló lé ọ̀pọ̀ àgbẹ̀ kúrò lóko àmọ́ tó wòye pé ètò ààbò Nàìjíríà ti gbópọn sí ju tí tẹ́lẹ̀ lọ..
bbc
yo
Èyí ló mú àwọn àgbẹ̀ ni ẹkùn ìwọ̀-oòrùn ní orílẹ̀ èdè yìí ṣe gbé ìpàdé àpérò kan idẹ láti wá ojútùú sọ́rọ̀ ẹbí tó gbòde kan lásìkò yìí.
bbc
yo
Dàṣàolu ni lóòótọ́ ni pé ọ̀rọ̀ ààbò ló lé ọ̀pọ̀ àgbẹ̀ kúrò lóko àmọ́ tó wòye pé ètò ààbò Nàìjíríà ti gbópọn sí ju ti tẹ́lẹ̀ lọ.
bbc
yo
O ro wọ́n láti má bẹ̀rù lati padà sí ọkọ, pé àìsí ètò ààbò ní Nàìjíríà tí ń lọ sí òkun ìgbàgbé..
bbc
yo
O ro wọ́n láti má bẹ̀rù lati padà sí ọkọ, pé àìsí ètò ààbò ní Nàìjíríà tí ń lọ sí òkun ìgbàgbé.
bbc
yo
Ó fi kún ọ̀rọ̀ rẹ pé àwọn àgbẹ̀ ní agbègbè ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà ti ṣetán láti mú ọ̀rọ̀ àìsí oúnjẹ kúrò ní orílẹ̀ èdè yìí, pé àwọn ti ṣetán láti rí dájú pé à ń pèsè oúnjẹ tó máa tó ṣẹ́kù fáwọn èèyàn Nàìjíríà..
bbc
yo
Ó fi kún ọ̀rọ̀ rẹ pé àwọn àgbẹ̀ ní agbègbè ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà ti ṣetán láti mú ọ̀rọ̀ àìsí oúnjẹ kúrò ní orílẹ̀ èdè yìí, pé àwọn ti ṣetán láti rí dájú pé à ń pèsè oúnjẹ tó máa tó ṣẹ́kù fáwọn èèyàn Nàìjíríà.
bbc
yo
Ó ní “A gbọdọ̀ mọ àwọn tí wọn ń ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀ ní ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan, kí àkọọ́lẹ̀ fún gbogbo àwọn tó ń ṣiṣẹ́ àgbẹ̀ ní Nàìjíríà kí a lè jẹ àǹfàní ìjọba bó ṣe tọ́ àti bó ṣe yẹ.".
bbc
yo
Ó ní “A gbọdọ̀ mọ àwọn tí wọn ń ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀ ní ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan, kí àkọọ́lẹ̀ fún gbogbo àwọn tó ń ṣiṣẹ́ àgbẹ̀ ní Nàìjíríà kí a lè jẹ́ àǹfàní ìjọba bó ṣe tọ́ àti bó ṣe yẹ.” Alága náà fi kún pé òun ránṣẹ́ sí mínísítà fún ọ̀rọ̀ àgbẹ̀ láti máa ṣe àbẹ̀wò sí àwọn ìgbèríko kí wọ́n le mọ bí ibi tí iṣẹ́ àgbẹ̀ dé dúró ní orílẹ̀ èdè yìí..
bbc
yo
Ó ní “A gbọdọ̀ mọ àwọn tí wọn ń ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀ ní ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan, kí àkọọ́lẹ̀ fún gbogbo àwọn tó ń ṣiṣẹ́ àgbẹ̀ ní Nàìjíríà kí a lè jẹ́ àǹfàní ìjọba bó ṣe tọ́ àti bó ṣe yẹ.” Alága náà fi kún pé òun ránṣẹ́ sí mínísítà fún ọ̀rọ̀ àgbẹ̀ láti máa ṣe àbẹ̀wò sí àwọn ìgbèríko kí wọ́n le mọ bí ibi tí iṣẹ́ àgbẹ̀ dé dúró ní orílẹ̀ èdè yìí.
bbc
yo
Dàṣàolu ni sise eyi ni yoo fun Minisita naa ni anfani lati mo awon ohun to n je awon agbe niya kaakiri agbegbe won ati pe won yoo mo ona to to lati wa atunṣe si gbogbo awon iṣoro naa..
bbc
yo
Dàṣàolu ni sise eyi ni yoo fun Minisita naa ni anfani lati mo awon ohun to n je awon agbe niya kaakiri agbegbe won ati pe won yoo mo ona to to lati wa atunṣe si gbogbo awon iṣoro naa.
bbc
yo
Lára ohun tó wáyé níbi àpérò náà ni bí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ àti ẹgbẹ́ àwọn darandaran, M&tti Allah ṣe tọwọ́bọ àdéhùn aláfíà láàárín àwọn méjèèjì pé àwọn máa ri dájú pé kò sí ogun tàbí ọ̀tẹ̀ láàárín àwọn èyí tó lè ṣàkóbá fún ààbò pípèsè oúnjẹ..
bbc
yo
Lára ohun tó wáyé níbi àpérò náà ni bí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ àti ẹgbẹ́ àwọn darandaran, M&tti Allah ṣe tọwọ́bọ àdéhùn aláfíà láàárín àwọn méjèèjì pé àwọn máa ri dájú pé kò sí ogun tàbí ọ̀tẹ̀ láàárín àwọn èyí tó lè ṣàkóbá fún ààbò pípèsè oúnjẹ.
bbc
yo
Iyalọ́jà gbogbo gbọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Folashade Tinúbú-ọjọ́ tí òun náà báwọn péjú síbi àpérò náà tẹnumọ́ pé títọwọ́ bọ ìwé àdéhùn aláfíà tí ẹ̀yà méjèèjì yìí buwọ̀lú yóò pọ́nkún ọ̀rọ̀ ètò ààbò ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
bbc
yo
Alága náà fi kún pé òun ránṣẹ́ sí Mínísítà fún ọ̀rọ̀ àgbẹ̀ láti máa ṣe àbẹ̀wò sí àwọn ìgbèríko kí wọ́n le mọ bí ibi tí iṣẹ́ àgbẹ̀ dé dúró ní orílẹ̀ èdè yìí.
bbc
yo
Iyalọ́jà gbogbo gbọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Folashade Tinúbú-ọjọ́ tí òun náà báwọn péjú síbi àpérò náà tẹnumọ́ pé títọwọ́ bọ ìwé àdéhùn aláfíà tí ẹ̀yà méjèèjì yìí buwọ̀lú yóò pọ́nkún ọ̀rọ̀ ètò ààbò ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
bbc
yo
Gbogbo iṣẹ́ tí ẹ̀dá bá sì ti ń ṣe, adura ni pé kò jẹ́ àṣelà.
bbc
yo
Gold nílùú Ìlọrin, nipinlẹ Kwara, sọ pe Eko nipa amojuto okoowo ni oun kọ nílé ẹkọ giga, amo iṣẹ́ àgbẹ̀ lo ń ṣe.
bbc
yo
Arábìnrin náà nígbà tó ń bá BBC sọ̀rọ̀ ṣàlàyé pé òun kò déédé di agbè ọlọ́sìn ẹja, adìyẹ àti irúgbìn.
bbc
yo
Ó ní iṣẹ́ àgbẹ̀ ni bàbá òun ṣe, òun nìkan sì ni ọmọ bàbá náà tó mú iṣẹ́ àgbẹ̀ náà ní ọ̀kúnkúndùn.
bbc
yo
Ó tó ọdún mẹtala tí arabinrin K.Gold ti ń ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀..
bbc
yo
Ó tó ọdún mẹtala tí arabinrin K.Gold ti ń ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀.
bbc
yo
Nǹkan tó sì mú kó yàtọ̀ sí àwọn àgbẹ̀ ọlọ́sìn ẹja bíi tiẹ̀ ni pé, ìtànṣán oòrùn, tí wọn ń pè ní Solar, ló fi ń ṣe iṣẹ́ rẹ̀..
bbc
yo
Nǹkan tó sì mú kó yàtọ̀ sí àwọn àgbẹ̀ ọlọ́sìn ẹja bíi tiẹ̀ ni pé, ìtànṣán oòrùn, tí wọn ń pè ní Solar, ló fi ń ṣe iṣẹ́ rẹ̀.
bbc
yo
Gold ṣàlàyé pé ọ̀wọ̀n gogò epo Betiro àti gáàsì, ló mú kí òun ronú kan lílọ Solar láti má a fi ṣe iṣẹ́..
bbc
yo
Gold ṣàlàyé pé ọ̀wọ̀n gógó epo Betiro àti gáàsì, ló mú kí òún ronú kan lílọ Solar láti má a fi ṣe iṣẹ́.
bbc
yo
“Lóòtọ́ ni owó tí mo ná sórí Solale náà pọ̀, àmọ́ èrè tó ń mú wá fún mi jẹ́ ìlọ́po méjì iye tí mo ń rí nígbà tí mo ń lo iná ìjọba.".
bbc
yo
“Lóòtọ́ ni owó tí mo ná sórí Solar náà pọ̀, àmọ́ èrè tó ń mú wá fún mi jẹ́ ìlọ́po méjì iye tí mo ń rí nígbà tí mo ń lo iná ìjọba.” Lára ìpèníjà tó tún ma ń rí ni pé gbogbo ìgbà kọ́ ni àwọn oníbàárà ma ń ra ẹja, èyí tó ma ń mú kí wọ́n ó na owó tí kò yẹ láti fi bo àwọn ẹja náà títí di ọjọ́ tí obìní bá wa..
bbc
yo
“Lóòtọ́ ni owó tí mo ná sórí Solar náà pọ̀, àmọ́ èrè tó ń mú wá fún mi jẹ́ ìlọ́po méjì iye tí mo ń rí nígbà tí mo ń lo iná ìjọba.” Lára ìpèníjà tó tún ma ń rí ni pé gbogbo ìgbà kọ́ ni àwọn oníbàárà ma ń ra ẹja, èyí tó ma ń mú kí wọn ó na owó tí kò yẹ láti fi bo àwọn ẹja náà títí di ọjọ́ tí obìní bá wa.
bbc
yo
Kò ṣàì gba àwọn obìnrin bí tiẹ̀, tó lè ní èròńgbà láti ṣe ọ̀sìn ẹja, pé wọ́n gbọdọ̀ lèw ní sùúrù, nítorí kìí ṣe iṣẹ́ tó ma ń fún ni ní owó kíákíá..
bbc
yo
Kò ṣàì gba àwọn obinrin bí tiẹ̀, tó lè ní èròǹgbà láti ṣe ọ̀sìn ẹja, pé wọ́n gbọdọ̀ lèw ní sùúrù, nítorí kìí ṣe iṣẹ́ tó ma ń fún ni ní owó kíákíá.
bbc
yo
Bákan náà ló ní ó jẹ́ iṣẹ́ tó gba àmójútó púpọ̀, èyí tó túmọ̀ sí pé lílọ sí òde àríyá ní gbogbo ìgbà kò le ṣe.
bbc
yo
Bákan náà ló ní ó jẹ́ iṣẹ́ tó gba àmójútó púpọ̀, èyí tó túmọ̀ sí pé lílọ sí òde àríyá ní gbogbo ìgbà kò le ṣe (C) 2024 BBC.
bbc
yo
Lára ìpèníjà tó tún ma ń rí ni pé gbogbo ìgbà kọ́ ni àwọn oníbàárà ma ń ra ẹja, èyí tó ma ń mú kí wọ́n ó na ọwọ́ tí kò yẹ láti fi bo àwọn ẹja náà títí di ọjọ́ tí obìkú bá wà.
bbc
yo
Orísun aworan, Niger State govt ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kọkànlá, oṣù kẹta ọdún 2024 ni Ààrẹ Bólá Tinubu ṣe àbẹ̀wò sí ìpínlẹ̀ Niger lati ṣe ifilọlẹ àtúnse pápákọ̀ òfúrufú èyí tí ìjọba ìpínlẹ̀ náà ṣẹ̀ṣẹ̀ tún ṣe, tí wọ́n sì sọ ní orúkọ rẹ̀.
bbc
yo
Tinubu yoo tun ṣe ifilọlẹ iṣẹ akanṣe eto ogbin Niger State Agricultural Revolution Project ati ẹka eto Hajj ni pápákọ̀ ofurufu naa.
bbc
yo
Àmọ́ ṣíṣe àyípadà orúkọ pápákọ̀ òfúrufú ìpínlẹ̀ Niger sí orúkọ Ààrẹ ló ti ń fa awuyewuye, tí àwọn èèyàn sì ń béèrè pé kí ló dé tí ìjọba fi ń pààrọ̀ orúkọ pápákọ̀ òfurufú náà.
bbc
yo
'dr Abubakar Imam kagára International Airport' ní orúkọ pápákọ̀ òfúrufú náà ṣáájú kí wọ́n tó yí orúkọ rẹ̀ padà..
bbc
yo
Ni ọjọ aje, ojo Kọkànlá, oṣu Kẹta ọdun 2024 ni Aare Bola Tinubu ṣe abẹwo si Ipinle Niger lati ṣe ifilọlẹ atunṣe pápákọ̀ ofurufu eyi ti Ijọba Ipinle naa se tun se, ti wọn si sọ ni orukọ rẹ.
bbc
yo
‘dr Abubakar Imam kágára International Airport’ ní orúkọ pápákọ̀ òfurufú náà ṣáájú kí wọ́n tó yí orúkọ rẹ̀ padà.
bbc
yo
Dókítà Abubakar káfọ́tò lọ jẹ́ ògbóǹtarìgì akọ̀wé àti akọ̀ròyìn tó kọ́kọ́ kọ ìwé ìròyìn ní èdè Hausa “Gaskiya ta fi Kwabo” ní ọdún 1939..
bbc
yo
Dókítà Abubakar káfọ́tò lọ jẹ́ ògbóǹtarìgì akọ̀wé àti akọ̀ròyìn tó kọ́kọ́ kọ ìwé ìròyìn ní èdè Hausa “Gaskiya ta fi Kwabo” ní ọdún 1939.
bbc
yo
Abubakar kágára jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òǹkọ̀wé ní ẹkùn àríwá Nàìjíríà tí ipa tí ó kó nínú ìdàgbàsókè èdè Hausa kò kéré rárá..
bbc
yo
Abubakar kágára jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òǹkọ̀wé ní ẹkùn àríwá Nàìjíríà tí ipa tí ó kó nínú ìdàgbàsókè èdè Hausa kò kéré rárá.
bbc
yo
Ìbéèrè tí àwọn lámèyítọ́ ń béèrè ni pé kí ló dé tí wọ́n fẹ́ yọ orúkọ ẹni tó ti ṣiṣẹ́ takuntakun bíi ti kágára kúrò lára pápákọ̀ òfurufú náà..
bbc
yo
Ìbéèrè tí àwọn lámèyítọ́ ń béèrè ni pé kí ló dé tí wọ́n fẹ́ yọ orúkọ ẹni tó ti ṣiṣẹ́ takuntakun bíi ti kágára kúrò lára pápákọ̀ òfurufú náà.
bbc
yo
Onímọ̀ nípa ètò òṣèlú kan tí kò fẹ́ kí wọ́n dárúkọ òun tó bá BBC News Pidgin sọ̀rọ̀ ni tó bá jẹ́ pé òun ni ààrẹ Tinúbú ni, òun kò ní gbà kí wọ́n ṣe àyípadà orúkọ náà sí orúkọ òun..
bbc
yo
Onímọ̀ nípa ètò òṣèlú kan tí kò fẹ́ kí wọ́n dárúkọ òun tó bá BBC News Pidgin sọ̀rọ̀ ní tó bá jẹ́ pé òun ni ààrẹ Tinúbú ni, òun kò ní gbà kí wọ́n ṣe àyípadà orúkọ náà sí orúkọ òun.
bbc
yo
Gomina ipinle Niger, Mohammed Umar Wise so pe idi ti awon fi dawọ oruko naa ni lati mọrírì ipa ti Tinubu ti ko si idagbasoke Niger, orile ede Naijiria ati ile Adulawo lapapo igba to gba akoso ijoba Naijiria..
bbc
yo
Gomina ipinle Niger, Mohammed Umar Yise so pe idi ti awon fi itan oruko naa ni lati mọrírì ipa ti Tinubu ti ko si idagbasoke Niger, orile ede Naijiria ati ile Adulawo lapapo lẹ́nu igba to gba akoso ijoba Naijiria.
bbc
yo
Àmọ́ onímọ̀ náà ni ó yẹ kí gómìnà ww ṣe àkànṣe iṣẹ́ ńlá kan gbòógì tó máa sọ ní orúkọ Ààrẹ..
bbc
yo
Àmọ́ onímọ̀ náà ni ó yẹ kí gómìnà ww ṣe àkànṣe iṣẹ́ ńlá kan gbòógì tó máa sọ ní orúkọ Ààrẹ.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Fáan kò ì tíì pé ọdún kan, ní ọjọ́ kìíní ọdún 2023 ní iléeṣẹ́ tó ń rí sí ètò ìrìnnà òfurufú gbé àtẹ̀jáde kan jáde pé àwọn máa ṣe àyípadà orúkọ pápákọ̀ òfurufú Minna International Airport àtàwọn pápákọ̀ òfurufú mẹ́rìnlá mìíràn ní Nàìjíríà..
bbc
yo
Orísun àwòrán, fàan kò ì tíì pé ọdún kan, ní ọjọ́ kìíní ọdún 2023 ní iléeṣẹ́ tó ń rí sí ètò ìrìnnà òfurufú gbé àtẹ̀jáde kan jáde pé àwọn máa ṣe àyípadà orúkọ pápákọ̀ òfurufú Minna International Airport àtàwọn pápákọ̀ òfurufú mẹ́rìnlá mìíràn ní Nàìjíríà.
bbc
yo
Nínú àtẹ̀jáde náà ni wọ́n ti kéde pé pápákọ̀ òfúrufú Maiduguri ni àwọn ti yí orúkọ rẹ padà sí pápákọ̀ Muhammadu Buhari tó jẹ́ orúkọ Ààrẹ àná ní Nàìjíríà..
bbc
yo
Nínú àtẹ̀jáde náà ni wọ́n ti kéde pé pápákọ̀ òfúrufú Maiduguri ni àwọn ti yí orúkọ rẹ padà sí pápákọ̀ Muhammadu Buhari tó jẹ́ orúkọ Ààrẹ àná ní Nàìjíríà.
bbc
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n yí orúkọ pápákọ̀ òfúrufú ìpínlẹ̀ Ebon ní ìlà oòrùn gúúsù Nàìjíríà padà sí orúkọ Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí ni ilé aṣòfin àgbà, Chuba ọkàdìgbò..
bbc
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n yí orúkọ pápákọ̀ òfúrufú ìpínlẹ̀ Ebon ní ìlà oòrùn gúúsù Nàìjíríà padà sí orúkọ Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí ní ilé aṣòfin àgbà, Chuba ọkàdìgbò.
bbc
yo
“Kí ni ìdí tí wọ́n fẹ́ fi yí orúkọ pápákọ̀ òfúrufú náà padà láì tíì pé ọdún kan tí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀ sẹ́yìn? Kí ni ipa tí yíyí orúkọ náà padà yóò ní lórí ètò ọ̀rọ̀ ajé ìpínlẹ̀ Niger? Èyí ni ìbéèrè tí onímọ̀ náà ń béèrè nígbà tó ń bá BBC sọ̀rọ̀..
bbc
yo
Kò ì tíì pé ọdún kan, ní ọjọ́ kìíní ọdún 2023 ni iléeṣẹ́ tó ń rí sí ètò ìrìnnà òfurufú gbé àtẹ̀jáde kan jáde pé àwọn máa ṣe àyípadà orúkọ pápákọ̀ òfurufú Minna International Airport àtàwọn pápákọ̀ òfurufú mẹ́rìnlá mìíràn ní Nàìjíríà.
bbc
yo
“Kí ni ìdí tí wọ́n fẹ́ fi yí orúkọ pápákọ̀ òfurufú náà padà láì tíì pé ọdún kan tí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀ sẹ́yìn? Kí ni ipa tí yíyí orúkọ náà padà yóò ní lórí ètò ọ̀rọ̀ ajé ìpínlẹ̀ Niger? Èyí ni ìbéèrè tí onímọ̀ náà ń béèrè nígbà tó ń bá BBC sọ̀rọ̀.
bbc
yo
Ijoba Ipinle Niger ni awon ti so ile eko Gbogbonìṣe ipinle naa kan to wa ni Zúngẹ̀ru ni oruko Dokita kagára nitori ile eko naa ba ise re mu..
bbc
yo
Ìjọba ìpínlẹ̀ Niger ni àwọn ti so ilé ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe ìpínlẹ̀ náà kan tó wà ní Zúngẹ̀ru ni orúkọ Dókítà Kágára nítorí ilé ẹ̀kọ́ náà bá iṣẹ́ rẹ̀ mu.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Niger State govt ewé, yàtọ̀ sí awuyewuye tó ń wáyé látàrí àyípadà orúkọ náà, Tinúbú yóò tún ṣe ìfilọ́lẹ̀ àkànṣe ètò ọ̀gbìn kan ní ìpín Niger..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Niger State govt ewé, yàtọ̀ sí awuyewuye tó ń wáyé látàrí àyípadà orúkọ náà, Tinúbú yóò tún ṣe ìfilọ́lẹ̀ àkànṣe ètò ọ̀gbìn kan ní ìpín Niger.
bbc
yo
Gomina Umaru Yw ti maa ń sọ wí pé ìpínlẹ Niger yóò tó maa pèsè oúnjẹ tí yóò tó wọ́n jẹ ní ìpínlẹ̀ náà..
bbc
yo
Gomina Umaru ww ti maa n sọ wi pe ipinlẹ Niger yoo to maa pese ounjẹ ti yoo to won je ni ipinle naa.
bbc
yo
Àkànṣe ètò ọ̀gbìn náà tí wọ́n fi lọ́lẹ̀ náà ní Total Agricultural support Programme (tasi) èyí tó jẹ́ àjọṣepọ̀ pẹ̀lú iléeṣẹ́ Brazil kan..
bbc
yo
Àkànṣe ètò ọ̀gbìn náà tí wọ́n fi lọ́lẹ̀ náà ní Total Agricultural support Programme (tasi) èyí tó jẹ́ àjọṣepọ̀ pẹ̀lú iléeṣẹ́ Brazil kan.
bbc
yo
Wọ́n ní ìrètí wa pé ètò náà yóò pọ́nkùn ìpèsè oúnjẹ àti iṣẹ́ fún àwọn aráàlú..
bbc
yo
Ẹ̀wẹ̀, yàtọ̀ sí awuyewuye tó ń wáyé látàrí àyípadà orúkọ náà, Tinúbú yóò tún ṣe ìfilọ́lẹ̀ àkànṣe ètò ọ̀gbìn kan ní ìpín Niger.
bbc
yo
Wọ́n ní ìrètí wa pé ètò náà yóò pọ́nkùn ìpèsè oúnjẹ àti iṣẹ́ fún àwọn aráàlú.
bbc
yo
Gomina Umaru Yw ti maa ń sọ wí pé wón Niger yóò tó máa pèsè oúnjẹ tí yóò tó wọ́n jẹ ní ìpínlẹ̀ náà.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà ti kéde pé àwọn yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní pín oúnjẹ káàkiri orílẹ̀èdè náà, láti tako ìṣòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ tó gbòde lásìkò yìí.
bbc
yo
Mínísítà fún ètò ọ̀gbìn àti ìwádì óbí, Abubakar Kyarí ló kéde ìgbélé yìí lọ́jọ́ Ajé.
bbc
yo
Kyarí ṣàlàyé pé òun mọ bí nǹkan ṣe nira fún ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà lásìkò yìí, tó sì ń fi ń dá wọn lójú pé ìjọba ń sa gbogbo akitiyan rẹ̀ láti rí pé wọ́n wa ojutu sí ìṣòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ.
bbc
yo
“Pẹlu bí nǹkan ṣe nira yìí, mò ń fi dáyín lójú pé àdéhùn wá sí ìlú kò yipada.
bbc
yo
Ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà ti kéde pé àwọn yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní pín oúnjẹ káàkiri orílẹ̀èdè náà, láti tako ìṣòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ tó gbòde lásìkò yìí.
bbc
yo