Datasets:
audio
audioduration (s) 2.98
12.5
| English
stringlengths 27
137
| Yoruba
stringlengths 29
177
|
---|---|---|
Welcome can you tell me whats wrong | Ẹ káàbọ ṣé ẹ lè sọ fún mi ohun tó ń ṣe ẹ |
|
If it happens at all it will be minor like a slight fever or swelling Shall we proceed | Rárá ó bí ó bá tilẹ wa maa ṣẹlẹ papaa yii o jẹ bi awon eewu kékeké bí ara gbi gbóná tàbí oju abi ti a tifun ko wu sẹrẹfẹ Ṣé kí a bẹrẹ si fun labẹrẹ naa |
|
Welcome Can you tell me whats wrong with your stomach | Ẹ káàbọ n jẹ ẹ le sọ ohun ti sí inú yin fun mi |
|
I have stomach pain and I vomit frequently | Mo ní irora ní inú mi ee ibi sì gbe mi ni gbogbo ígbà |
|
Have you eaten recently or is there something you think caused this | Ṣé o ti jẹun lẹnu lọlọ yi ni abi kilẹẹ yin ro to le faa inu runrun yi fun yin |
|
I ate meat that wasnt wellcooked and Ive had diarrhea since then | Mo jẹ ẹran kan ti n kosi jina dáadáa eyin igba yi ni inu mi bẹrẹ si ni rọ lu ra wọn ti mo si bẹrẹ si ni ya gbẹ ti mo si ibii |
|
We will give you medicine for this and recommend that you avoid oily or heavy foods | A fun yin ní oògùn ti o tọ ju àrùn yìí sugbon oo arọ yin ki ẹẹ ma jẹ ounjẹ ti o ni epoo tabi tó wuwo lara yin fun gba di ẹẹ |
|
Welcome how are you feeling | Ẹ káàbọ ṣé ẹ lè sọ un to se yin fun mi |
|
Im fine but I have pain in my body and joints | Ara mi yá ṣùgbọn gbogbo ara loro mi ati gbogbo rikerike ara mi |
|
Have you been drinking enough water or have you been taking your folic acid supplements | Ṣé ẹ mu ọpọlọpọ omi bayi Ṣé ẹ si lo folic acid bo se tọ ati bo si yẹ |
|
Yes but the pain hasnt subsided yet | Bẹẹni ṣùgbọn irora náà kọ kò lọ |
|
I am not feeling well I have body pains and a headache | Ara mi kò yá mo ara gbogbo ara lo ro mi ori fọ na |
|
Continue with the folic acid We will run a test to see if its due to anemia or water retention | ẹ tẹ si wa ju lati ma lo folic acid naa a ṣe àyẹwo fun yin láti mọ bóyá omi arayi ló ti pọ ju nii tabi nkan mi lo fa ara riro fun yin |
|
Do you have a fever or is your body hot | Ṣé o ní iba tàbí ara gbóná ni |
|
Yes my body is very hot and I feel weak | Bẹẹni ara mi gbóná gidigidi ara mi si fu yẹ ara mi wu |
|
It seems you may have malaria We will test your blood to confirm Meanwhile drink plenty of water and take this medicine three times daily | O ma da bi pe e fe ni iba maa ni yẹ A máa ṣe àyẹwọn ẹjẹ yin ati leri aridajú owon ti o se yin sugbon na e gba oògùn yìí ki e ma lo lẹẹmẹta lójó ki esi ma mu opolopo omi pelu rẹẹ |
|
Welcome Has this child received all the necessary vaccinations | Ẹ káàbọ Ṣé ọmọ yìí ti gba gbogbo abẹrẹ rẹ tó yẹ ko gba pe ni |
|
No we havent taken the vaccination for the new infection yet | Rárá a kò tíì gba abẹrẹ fún àrùn àkóràn tuntun yìí to sẹ de |
|
It is important for your child to get the vaccine It will protect their health against severe infections | Ó ma ṣe pàtàkì fún ọmọ yin láti gba abẹrẹ náà yii dáàbò kuro lara kuro lọ dọ àrùn tó ṣòro láti tọju |
|
Does the vaccine have any possible side effects | Ṣé abẹrẹ náà ko ni ewu kankan ti oole jáde leyi ti a ba gba tan |
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 78