text
stringlengths
1
44.6M
Ìṣàsopọ̀ Àìrí Ìkọ̀kọ̀
Àwọn ọ̀jọ̀gọ́n, àwọn Yoda àti Obi-Wan Kenobid mi, tí wọ́n mú ìmọ òjìni wọn wá láti jẹ́ kí iṣẹ́ yìí di ǹkan tó dà lónì.
Ṣùgbọ́n ó déédé dúró, ó sì wẹ̀yìn wo ìyá rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan sí i –bí igbà tó bá fẹ́ bèèrè pé “nígbà wo ni bàbá máa padà dé?” Kò sẹ́ni tó mọ̀. Ó jọ ọ́ pé Làbákẹ́ ti fèsì.
Àyè fún àtúnpè-ẹjọ́
#BringBackOurGirls àti #ArewaMeToo ṣe àtúntò sí ìgbàwí ètò ìṣèlú ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ìṣòro kan ni ti àìrí ìwé ìrìnnà gbà, òmíràn ni ti owó ìrìnàjò ọ̀fẹ́ gọbọi tí ó wọlẹ̀ nítori n kò le è lọ si àpérò.
Facebook ló léwájú gẹ́gẹ́ bí i gbàgede ààyò ọ̀pọ̀ ọmọ orílẹ̀-èdèe Nàìjíríà pẹ̀lú òǹlò ẹgbẹẹgbẹ̀rún 22, tí gbàgede àwòrán-àtohùn YouTube (ẹgbẹẹgbẹ̀rún 7 àti jù bẹ́ẹ̀ lọ) tẹ̀lé e, Twitter (ẹgbẹẹgbẹ̀rún 6) àti Instagram (ẹgbẹẹgbẹ̀rún 5.7).
Síbẹ̀, Ìṣèjọba Assad ń tẹpẹlẹ mọ́ sísọ òfegè ìròyìn àti irọ́ lórìṣirísi bẹ́ẹ̀ ni ó tún ṣe àdínkù iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ti ní COVID-19.
Mo fún pọ̀ níbí, pẹ̀lu mílíọ́nù méje ènìyàn ní ẹ̀gbẹ́ mi lónì.
Ní ọjọ́ 17 oṣù Ẹrẹ́na, ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti kọ́kọ́ sọ pé kí wọ́n fi òfin de àwọn ọkọ̀ òfurufú tí ó ń bọ̀ láti àwọn orílẹ̀ èdè tí àrùn náà ti gbilẹ̀ bí i United Kingdom àti China, kí wọ́n tó dúró di ọjọ́ kejì kí wọ́n tó fi òfin náà múlẹ̀.
Ó fi etí àti ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ̀ wíwú han màmá.
Ó múnú mi dùn láti ronú wí pé gbogbo èyí, iṣẹ́ aláìlẹ́gbẹ́ tí mò ń ṣiṣẹ tọ̀ – àti ìjẹ́ òótọ́ pé mo dúró níbí, báa yín sọ́rọ̀ lónì -- gbogbo rẹ̀ wá látara èrò kékeré tí mo ní nígbà tí mo jókò lẹ́yìn ní sẹminá nígbà tí mo wà lọ́mọ ogún ọdún.
Alákòóso ọ̀rọ̀-ìfiwọlé sábà máa ń ní ọ̀nà láti ṣe àkópamọ́ fáìlì, tàbí kí o lo iṣẹ́ àkópamọ́ tó wọ́pọ̀.
Bí ó ṣe rí fún màmá gan-an rè é.
Ìtan ìmọ̀-ìṣègùn ni, ṣùgbọ́n jù bẹ́ẹ̀ lọ, ìtàn àwùjọ ni.
Àwòrán Làbákẹ́ tí ó gba àmì ẹ̀yẹ ipò kìn-ín-ní nínú ìfigagbága magasíìnì Lọ́ńdọ́ọ̀nù nìyẹn.
Bí ó bá se abọ́ ìgbọ̀nṣẹ̀ kan fún un bi oúnjẹ, Àlàmú á jẹ ẹ́ pẹ̀lú ìgbádùn àti ìtẹ̀lọ́rùn.
Tí a bá sì gbìyànjú láti pa ojú dé, àwọn ẹ̀ṣọ́ á da iyẹ̀pẹ̀ sí wa. Wọ́n á sì wọ ìbòjú padà.
Mẹ́rin nínú àwọn ilé-iṣẹ́ márùn tó wà lókè ténté jẹ́ ilé-iṣẹ́ kùkúyè, ìdókówò tèmi, onímọ̀ nípa ààrun jẹjẹrẹ.
Ṣé kì í ṣe pé ó kàn dára sí ilé lásán ni, kàkà kí ó fi kọ́ ilé?
Tí o bá dókówò ní ilé-iṣẹ́ kan, o ti ní díẹ̀ lára ilé-iṣẹ́ yẹn.
Ati àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin tó dá ṣáṣá tí wọ́n ń fi agbára wọn hàn nípa bíbẹ́ wọnú ọkọ̀ láti ojú fèrèsé kéé-kèè-kééọkọ̀!
Ǹjẹ́ àmì orí ayélujára yìí yóò ṣe amọ̀nàa ìgbèjà ẹ̀tọ́ tí kì í ṣe ti orí ayélujára tí yóò béèrè fún àtúnṣe tí yóò sọ ilé ẹ̀kọ́ gíga ifásitì di ibi ààbò fún àwọn obìnrin bí?
Ìwò lẹ́gbẹ́lẹ́gbẹ́
Nípa pípésè àmì ìdánimọ̀ tàbí òǹkà ìdánimọ̀
Àwòrán ìpolongo orí ayélujára tí Provea taari síta.
Làbákẹ́ sin Àlàmú lọ sí tíátà ní gbàgede Luchester láti lọ wòran ijó rẹ̀. Ó jẹ́ ìran tó dùn-ún wò. Josephine jó ijo náàdáadáa tó wú àwọn ènìyàn lórí. Inú Àlàmú dùn yàtọ̀ sí ti àwọn èrò ìwòran yòókù.
Boniface Igbeneghu, Ifásitì Èkó, tí a ká ìwà àṣemáṣe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìrin nínú ìwádìí abẹ́lẹ̀ tí BBC ṣe.
Ẹ̀bùn ìfura sọ́rọ̀ ọmọ àwọn ìyá mìíràn ni àlá, àwọn mìíràn níagbára àti rí nǹkan. Àwọn abiyamọ tòótọ́ mìíràn máa ń rí àmì – àmìbí i kí íle-ọmọtí wọ́n gbé ọmọ sí fún oṣù mẹ́sàn-án déédé dún, tàbí kí egúngún ẹ̀yìn tí ọmọ wọn ń gùn ní kékeré déédé sọ kúlú.
Ikọ̀ awakọ̀ òfuurufú olóbìnrin àkọ́kọ́ irúu rẹ̀ ní Mozambique | A lo àwòrán pẹ̀lú àṣẹ láti ọwọ́ Meck Antonio.
Ní ti Àlàmú, Èṣùníyì ti sọ fún màmá pé kò séwu lóko mọ́.
Wọ́n ń tọpa wọn pẹ̀lú àwọn ẹ̀rọ inú ilé àti àwọn ẹ̀rọ arannilọ́wọ́ nínu ilé wọn.
Ṣe ẹ ò ní nǹkan tí ẹ fẹ́ fi kún àwọn nǹkan tíẹ ti sọ fún wa?”
Ọ̀kọ̀ọ̀kan ìlà nínú iṣẹ́ yìí ni ó ń ṣe àkọsílẹ̀ ìlò gbogbo tí òǹṣàmúlò lo ohun àmúlò kan pàtó.
Ìkìlọ̀: Orúkọ ohun-èlò nìkan ni yóò yípadà, orúkọ titun náà yóò ṣiṣẹ́ papọ̀ yóò sì ṣàfikún ìbágbàmu lórí àwọn ẹ̀rọ mìíràn tí ó sọ pọ̀ mọ́ ohun-èlò yìí.
Nínú yàrá, Làbákẹ́ bọ́ ìfasokọ́sí, ó sì bẹ̀rẹ̀ si í i yọ àwọn aṣọ rẹ̀. Kíá, ó ti kó wọn sínú àpótí aṣọ. Ohun ẹ̀ṣọ́ ara ni ókún inú kọ́ńbọ́ọ̀dù méjì nínú yàrá náà, ó sì kó àwọn nǹkan inú rẹ̀ sínú apẹ̀rẹ̀ rafia òfìfo méjì ní kíákíá.
Kardiata Malick Diallo, tí ó jẹ́ igbákejì, sọ ọrọ àròjinlẹ̀ ní ilé Ìgbìmọ̀ aṣòfin Mauritania láti máà jẹ́ kí àwọn ènìyàn gbàgbé, tí ó sì fi ẹ̀sùn kàn ààrẹ tí ó wà lórí oyè pé ó ń dáàbò bo àwọn oníṣẹ́-ibi náà, tí wọ́n ṣì ń dipò gíga mú nínú ìjọba nígbà tí wọn kò tí ì wá nǹkan ṣe sí ẹ̀tọ́ àwọn olùfarapa:
Jẹ́ kí àwọn òkú ó sọ ìtàn nípa Hong Kong
Ẹ àwòran ara yín bí ẹni tó ń wakọ̀ ní ọnà tóóró kan nílẹ̀ Adúláwọ̀, bí o ṣe ń wakọ̀ lọ, o gbojú sí ẹ̀gbẹ́, ǹkan tí o sì rí rèé: o rí àyè tí wọ́n sìnkú sí.
A kì í mọ̀ ọ́n rò bí ẹlẹ́jọ́.
Ẹ̀rọ iṣẹ́ tí o ni ìdánimọ̀ yìí kò ní ìkànnì tí ó yẹ
Aṣẹ yìí gba ẹnìkẹnì láàyè láti lè lò iṣẹ́ yìí fún ète èyíkéyìí, pàápàá fun ìpolówó ọjà.
[Òkè] Ààrẹ ÖSYM sọ̀rọ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́ lẹ́yìn ìdánwò!
Àlàmú... Àlàmú…' Làbákẹ́ tesíwájú, 'Kí ló ṣẹlẹ̀ sí iṣẹ́ rẹ?'
Ilẹ̀-Adúláwọ̀ rí àbọ̀ ẹgbẹẹgbẹ̀rún-lọ́nà-ẹgbẹ̀rún owóo dollar láti ọ̀dọ̀ Ilé-ìfowópamọ́sí ńláńlá fún ìgbéfúkẹ́ Iléeṣẹ́ ọgbọ́n àtinudá
Títí di ìgbà tí ó máa fi kó ẹrù rẹ̀ lọ pátápátá, kí oníkálùkù ní ìtẹ́lọ̀rùn pẹ̀lú ohunkóhun tó bá rí jẹ.
Àdánwòo Alaa jọ ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè Íjípìtì tí ó wà ní ẹ̀yin gádà nítorí akitiyan wọn nípa ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn.
Ìpinnu Beijing kò ju láti pa ohun gbogbo tí ó bá tan mọ́n ìṣẹ̀lẹ̀ ọjọ́ 4 oṣù Òkúdù rẹ̀ lórí ayélujára.
Ojú kì í pọ́n ẹdun kó dẹni ilẹ̀; ìṣẹ́ kì í ṣẹ́ igún kó di ojúgbà adìẹ.
Kí Àlàmú tó ráyè láti yanjú àwọn ìṣòro wọ̀nyí ni àwọn mìíràn tí ó le ju èyí yóò tún dé bá a.
Superstition and lack of awareness behind witch-hunting in India
Ó wọ yàrá rẹ̀ lọ ní dídá ibòdè màmá kọjá! Ó kó sínú páńpẹ́ màmá! Páńpẹ́ babaláwo!
Ìdánwò ọdún yìí wáyé nínú àìgbọ́raẹniyé—àti pé kì í ṣe nítorí àjàkálẹ̀
Eéji pẹ̀lú Eéji máa ń fún un ní Aárùn-ún ní gbogbo ìgbà. Ìṣirò ayírí onímò ìṣirò.
Lẹ́yìn náà ni ó tún wo ọkọ ṛẹ̀. Làbákẹ́ doríkodò. Ẹ̀rín “ha ha ha ha” abàmì yẹn tún wá sí etí rẹ̀, ó gbọ́ ohùn ìfiniṣeyẹ̀yẹ́ àwọn aládùúgbò lẹ́ẹ̀kan sí i, ó tún rí awakọ̀ ọkọ̀ akẹ́rù tí ó ń ṣàpèjúwe bí orí ṣe yí tó.
Ẹ kọ̀ rò ó wò, tí wọ́n bá ṣe ìfilọ́lẹ̀ ilé-iṣẹ́ tuntun àyánrán kan lónì, ní ìparí oṣù Òkudù tó ń bọ̀, àwọn èròja ilé-iṣẹ́ yẹn ti pa mílíọ́nù méje ènìyàn.
“Àṣé ó tiè yé ọ Tinú?”, Làbákẹ́ túbọ̀ ń bá Tinú sọ̀rọ̀, “Àṣé gbogbo rẹ̀ yé ọ?,
A ò ní ǹkankan láti fi pamọ́.
Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ọmọ àṣètán-ń-nì, ẹ sùn lọbí igi
Gbogbo ìgbésíayé mi dẹ̀ ṣí sílẹ̀ lóòtọ́.
Nílé, Làbákẹ́ ti wá ń báìgbà yí, ó ń ṣọ́igbá rẹ̀, ó sì ń mú inú ara rẹ̀ dùn pẹ̀lú Tinú àti Sènábù.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ irọ́ olùrànlọ́wọ́ ààrẹ
“Ọlọ́run á ràn yín lọ́wọ́. Ọlọ́run á ṣí ojú yín àti etí yín. Ẹ ẹ́ lè ríran rí ara yín bí ẹ ṣe wàyìí. Àwa wí!”
Lẹ́yìn ọdún kọ́kànlá, òun ni ọmọ ìbílẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó gbẹjọ́rò ní ilé-ẹjọ́ gíga jùlọ.
Ó ní láti se nǹkan si i. Ni kíákíá si ni pẹ̀lú. O ní láti jáde síta kí o wá ìrànlọ́wọ́. Ẹ̀ ń ti ara yín mọ́ ilé fún gbogbo ọjọ́! Kò síì ṣòro tó níyanjú lọ́ nà yẹn!
Ìṣòro tó bá a lọ́wọ́lọ́wọ́ tó fún un.
Ìsọtasí ìwé àbá náà pa òfin náà ní àpakú finínfinfín — èyí kò sì jẹ́ kí ààrẹ ó bu ọwọ́ lù ú.
Ìbáṣepò rẹ̀ pẹ̀lú Làbákẹ́ kò dán mọ́rán rárá.
Hannan Gazi náà se àgbéjáde tirẹ̀:
Ìlú Washington la ti rà á, nígbà ìgbádùn àṣẹ̀ṣẹ̀ṣe ìgbéyàwó.
Làbákẹ́ sì ń ṣe jẹ́jẹ́.
Ní báyìí, ọ̀wọ́n yìí jẹ́ kí ìwà-ìbàjẹ́ tàn kálẹ̀ ní ẹ̀ka náà.
Reno Omokri, olùrànlọ́wọ́ ààrẹ àná, fi ẹ̀sùn kan Ezekwesili wí pé ẹgbẹ́ olóṣèlú APC ni ó ń lò ó fi ba ìjọba tí ó wà lórí àpèré jẹ́ àti láti "yẹpẹrẹ" ìjọba Ààrẹ Jonathan, nípa èyí náà ni ó fi lànà fún APC láti "gba ọ̀pá àṣẹ".
Lẹ́yìn ọjọ́ karùn-ún, Màmá bínú lọ ilé.
Olúborí ìdíje àròkọ Ìlọ̀rí Olúwatóbi ti iléèwé Mater Christi Catholic Girls' High School, Ìgede Èkìtì, Ìpínlẹ̀ Èkìtì, mú u wá sí ìrántí ìgbà àkọ́kọ́ tí òùn-ún ṣalábàápàdée rédíò nígbà tí òùn-ún wà ní ọmọ ọdún 5:
Nínú èsì kan sí TJournal, tí ó jẹ́ iléeṣẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti ìròyìn ẹ̀rọ alátagbà àti orí ayélujára.
Báwo la ṣe lè ṣe ìyẹn?
A ò nímọ̀ kankan tàbí àkóso lórí ọ̀nà tí àwọn tó ń rà, tà tí wọ́n sì ń lo dátà wa ṣe ń ṣe àkọsílẹ̀ wa àti àwọn ọmọ wa.
Bí àwọn aládùúgbò bá ní àǹfààní sí ilé Àlàmú, wọ́n á ti rí i pé Sènábù ṣì ń sùn lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹrù kékerénínú yàrá ìgbafẹ́ nínú ilé.
A fi ìwé pe Wakabi kí ó wá á sọ̀rọ̀ níbi ètò Àyájọ́ Àwọn Olùgbèjà Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ní Tanzania ọlọ́dọọdún tí Àgbáríjọ Olùgbèjà Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ti Tanzania (THRDC) jẹ́ olùgbàlejò.
Ǹkan tó tẹ̀le èyí ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fọ́rán ìbálópọ̀ ayédèrú tó ń ṣàfihàn àwọn ẹni-iyì lóbìnrin tí wọ́n jẹ́ ààyò àwọn ènìyàn.
Kí ni ó yá àpọ́n lórí tó fiṣu síná tó ń súfèé pé “bí a ti ń ṣe ni inú ń bí wọn”?
Làbákẹ́ pohùn réré, wọn ò mọ nǹkankan yàtọ̀ sí kí wọ́n kan èèyàn lábùkù, kí wọ́n ṣèké, kí wọ́n sìsọ̀rọ̀ banilórúkọjẹ́, wọn ti sọ irún ǹ kan bẹ́ẹ̀ sí etí rẹ̀ náà rí.
Ní oṣù ti ó kojá, mo ṣe alábàápàdé oníṣẹ́-ìròyìn tí ó wá láti Ìlà-oòrùn Ilẹ̀-adúláwọ̀ tí ó ń ṣe ìbéèrè fún ìwé ìrìnnà wọ Nàìjíríà. Wọ́n ní kí ó pèsèe ìwé-ẹ̀rí ìwákọ̀ọ ti akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ awakọ̀ tí yóò wá gbé e bí ó bá balẹ̀ ní pápá-ọkọ̀-òfuurufú!
Abẹ ìgbèkùn àwọn ọ̀gágun tí ó ti jagun fẹ̀yìntì àti àwọn asọ́mogbée wọn ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wà. Bí àpẹẹrẹ, Ọbásanjọ́ jẹ́ alẹ́nulọ́rọ̀ tí ó mọ àludé tòun àpadé bí àwọn Ààrẹ ṣe ń gba ipò láti ọdún 2007 sí 2015.
Gẹ̀gẹ̀ bí ìjábọ̀ ìròyìn, àwọn àgbàlagbà wọ̀nyí ṣe ikú pa ọkùnrin kan, ni ìgbìmọ̀ abúlée Panchayat ṣe dá wọn lẹ́bi.
Màmá bẹ̀rẹ̀ sì í tún yàrá náà ṣe lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó gbọn gbogbo jàǹkárìwọ̀ sílẹ̀, ó sì lé àwọn ááyán àti ọmọ-onílé lọ.
Àwọn ìpèníjà òṣèlú tí ó ń kojú wọn ní Hong Kong lẹ́yìn Àkójọpọ̀ Ẹgbẹ́ Alábùradà; 2014 Umbrella Movement kò ṣe àjòjì sí Chemi Lhamo, ṣùgbọ́n ó bá àwọn ará Hong Kong kẹ́dùn, ó pẹ̀tù sí wọn lọ́kàn pé kò kí wọ́n máà ṣe juwọ́ sílẹ̀:
A ti mú àdínkù bá ikú ọmọdé pèlú ìdá márùn-lé-láàdọ́rin (75%), ikú ìyá pẹ̀lú ìdá ọgọ́rin (80%).
Ó ń fi ara rẹ̀ ṣe yẹ̀yẹ́.
Àlàmú tiraka láti má jẹ́ kí ohun ṣíṣàn náà padà wá sí ẹnu rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èébì.
Àwọn ajìjàngbara sọ wípé ìgbàgbọ́-asán tí ó rinlẹ̀ ní ìgbèríko ni ó ń fa ìwà pálapalà náà.
Lẹ́yìn ìsẹ́jú márùn-ún géérégé, wọn pe Làbákẹ́ wọ yàrá kan, tí ọ̀kan ninú àwọn lọ́yà, ìyẹn Àkànní Mústàfá ti ń dúró láti gbà á lálejò.
Àwọn ni alága àwọn ẹgbẹ́ awakọ̀... Alága wa... Máa ń bá wa ṣére gan an...”, awakọ̀ náà sọ fún Làbákẹ́.
Ó wòye irú ipa tí ọ̀rẹ́ Àlàmú á tún fẹ́ kó nínú ọ̀rọ̀ náà.
Ó ká mi lára nípé iṣẹ́ẹ wa kò yé ikọ̀ ajagun yékéyéké.
Nítorí ìbẹ̀rù fún ààbò àwọn àlejòo rẹ̀, Shabuyeva fagilé ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò náà tí ó sì fi ètò mìíràn rọ́pòo rẹ̀.
“Ẹ tàsé rẹ̀ fún bí i ìṣẹ́jú díẹ̀ màdáámú, ó lọ lẹ́yìn ìgbà tí ó fẹ́rẹ̀ ẹ́ lè fìfẹ́ yí mi lórí, ó sì ṣèlérí láti wá gbé mi ní aago mẹ́ta ààbọ̀ gérégé.
Nípasẹ sísọ ìrírí náà ni àwọn ènìyàn ti má a ń rí ọgbọ́n bí wọ́n ṣe lè tọ́jú ara wọn, bí wọn ó ṣe sọ ọ́ bí wọn ó ṣe lo òògùn.
A kò le è ní ìwé-òfin tí ó fi ẹ̀tọ́ fún òmíràn ìkẹ́gbẹ́ kí ó tún wá fún ẹnìkan ní agbára láti mú ẹ̀tọ́ òmìnira ìkẹ́gbẹ́ kúrò.