Spaces:
Sleeping
Sleeping
Ilé - iṣẹ́ẹ Mohammed Sani Musa , Activate Technologies Limited , ni ó kó ẹ̀rọ Ìwé - pélébé Ìdìbò Alá... | |
Ilé - iṣẹ́ẹ Mohammed Sani Musa , Activate Technologies Limited , ni ó kó ẹ̀rọ Ìwé - pélébé Ìdìbò Alálòpẹ́ ( PVCs ) tí a lò fún ọdún - un 2019 , nígbà tí ó jẹ́ òǹdíjedupò lábẹ́ ẹgbẹ́ olóṣèlúu tí ó ń tukọ̀ ètò ìṣèlú lọ́wọ́ All Progressives Congress ( APC ) fún Aṣojú Ìlà - Oòrùn Niger , ìyẹn gẹ́gẹ́ bí ilé iṣẹ́ aṣèwádìí , Premium Times ṣe tẹ̀ ẹ́ |