text
stringlengths 23
128
| clean_label
stringclasses 7
values | clean_label_id
int64 0
6
| noisy_label
stringclasses 7
values | noisy_label_id
int64 0
6
|
---|---|---|---|---|
Abu Bakr al-Baghdad: Orílẹ̀èdè Amẹrika náà ti kọlu aṣaájú ẹgbẹ́ ISIS | world | 0 | world | 0 |
Number Plate: Ìlànà FRSC rèé láti gba nọ́mbà àdáni fún ọkọ̀ rẹ | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Facebook yóò bẹ̀rẹ̀ ìnáwó orí ayélujára 'GlobalCoin' lọ́dún 2020 | world | 0 | entertainment | 6 |
COZA: A ti wọ́gilé ìwọ́de lórí COZA tí a fẹ́ ṣe tẹ́lẹ́ nítorí... | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
Ẹ wo bí ìjíròrò ṣe lọ láàrin àwọn olùdíje gómìnà Kwara | politics | 4 | politics | 4 |
Soyinka: Ohun gbogbo ti dẹnu kọlẹ̀ la ṣe gbọdọ̀ gbé ìgbésẹ̀ pàjáwìrì | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Aguda Ogba Fire: Iná míì tún sọ ní Ọgba, nílùú Eko! | nigeria | 1 | politics | 4 |
Xenophobia: Ọrò ajé llè South Africa ti ń rẹ̀yìn lọ́wọ́lọ́wọ́ | africa | 5 | africa | 5 |
Afeez Owo: Abiyamọ gidi ní Funmi martins, ìyá ìyàwó mi | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Ondo Police: À ń wá Deji Adenuga tó dáná sun ènìyàn mẹ́jọ | nigeria | 1 | world | 0 |
APC: O jẹ́ tètè jẹ́wọ́ àwọn tó rán ọ níṣẹ́ torí àwa kìí fún apààyàn lówó | politics | 4 | nigeria | 1 |
CCT: Adájọ́ fẹ̀yìntì ní àwọn asòfin àpapọ̀ yẹ kó fòǹtẹ̀ lu ìgbẹ́jọ́ adájọ́ àgbà | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
2019 elections: Awọn jàǹdùkú yìnbọn f'éèyàn méjì nítorí owó ní Kwara | politics | 4 | nigeria | 1 |
Ayinla Kollington: Ìyàwó mí títí láéláé ni Salawa Abẹni | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Europa league: Ìjàmbà tún ṣe Ole àtàwọn ọmọ rẹ níwájú AZ Alkmaar, ọ̀mì ni wọ́n ta | sport | 3 | nigeria | 1 |
2019 Elections: Ìpàdé ìtagbangba BBC Yorùba ń ṣẹlẹ̀ ní gbọ̀ngàn fásitì ìlú Ilorin | politics | 4 | nigeria | 1 |
Ramadan: Àwọn mùsùlùmí tí kò bẹ̀rẹ̀ àwẹ̀ títí d'ìgbà tí wọ́n tó fojú r'óṣù | world | 0 | entertainment | 6 |
Xenophobia: Ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀ ni bàálù yóò lọ kó ọmọ Nàíjíríà wálé | africa | 5 | africa | 5 |
Èyí ni bí àwọn agbébọn ṣe gbé òṣìṣẹ́ Shell méjì, wọ́n tún pa àwọ̀n aláàbò wọ̀n ní Rivers | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Alaafin: Ẹ máa kọ́ àwọn ọmọ wa ní èdé àti àṣà Yorùbá | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Anambra mortuary: Ọ̀pọ̀lọpọ̀ òkú jóná di eérú nínú iná tó jó ní mọ́ṣúárì Anambra | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ìtàn Mánigbàgbé: Kí lo fẹ́ mọ̀ nípa ‘Ajala Travels’? | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Katsina: Ó di ìgbàkẹ́tà l'óṣù kan tí àṣírí ilé ìmúni nígbèkùn yóò tú síta ní àríwá Nàìjíríà | nigeria | 1 | world | 0 |
Olufunke Oshonaike: Ewu ń bẹ fún àwọn obìnrin tó ń fẹ́ ọkọ ọlọ́kọ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Ìpànìyàn: Agbébọn pa 16 ní Benue, jàǹdùkú 59 kú ní Zamfara | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Nigeria Swearing in 2019: Makinde ní omi tuntun rú, ìgbà ọ̀tun dé sí ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ | politics | 4 | politics | 4 |
Electoral bill 2018: Buhari àtàwọn aṣòfin àpapọ̀ leè gbéná wojú ara wọn láìpẹ́ | politics | 4 | politics | 4 |
Obasanjọ pàrọọwà sí Makinde: yàgò fún òṣèlú sọ ọ́ sápò | politics | 4 | politics | 4 |
Nigeria 2019 Elections: Tinubu ní òun yóò sàjọyọ̀ ìsẹ́gun lọ́sẹ̀ tó ń bọ̀ | politics | 4 | politics | 4 |
Botswana: Ìdí tí erin àti òkúta Dáyámọ́ǹdì yóò fi leè sọ olúborí èsì ètò ìdìbò ààrẹ | africa | 5 | politics | 4 |
Oluwo, ó yẹ kí o bọ̀wọ̀ fún ara rẹ - Olorì àná, Chanel Chin | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn: Iléeṣẹ́ aṣọ́bodè ní àṣìta ìbọn ló fa sábàbí | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
JAMB Result 2019: 34,120 akẹ́ẹ̀kọ́ ni kò ní èsì ìdańwò JAMB | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ondo Doctors‘ Strike: Ọ̀pọ̀ dókítà ni wọ́n jẹ́ lowó oṣù mẹ́ta sí mẹ́fà | health | 2 | health | 2 |
Nollywood: Taiwo Hassan, akọni òṣèré Yollywood tó jẹ́..... | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
BB Naija 2019: Ọlọ́pàá Gẹ̀ẹ́sì bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí Khafi lórí ẹ̀sùn ṣíṣe ìbálòpọ̀ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
End of a decade: Àwọn ìròyìn mẹ́wàá tó mí ilẹ̀ titi láàrin ọdún 2010-2019 | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
Electoral bill 2018: Èrèèdí wàhálà láàárín Buhari àtàwọn aṣòfin àpapọ̀ lórí òfin ìdìbò 2018 | politics | 4 | politics | 4 |
Onitsha market fire: Ilé tó lé ni 100 ló bá ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná lọ ní Onitsha | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Election Tribunal: INEC ní òfin kò ní kí èsì ìbò ààrẹ wà lórí ''server'' | politics | 4 | politics | 4 |