ending1
stringlengths
4
149
ending2
stringlengths
5
156
startphrase
stringlengths
7
179
labels
int64
0
1
split
stringclasses
7 values
Àwọn ọlọ́pàá ti ṣe ìlérí pé àwọn yóò pa ẹni tó bá ja ìjọba lólè
Àwọn ọlọ́pàá ti sọ pé owó wà fún ẹni tó bá ja ìjọba lólè
Àwọn ọlọ́pàá ti ṣe ìlérí pé, ẹni tó bá ja ìjọba lólè yóò gba ẹ̀bà láyé tí yóò lọ gba ọbẹ̀ lọ́run
0
yo
Àwọn ọlọ́pàá ti ṣe ìlérí pé àwọn yóò pa ẹni tó bá ja ìjọba lólè
Àwọn ọlọ́pàá ti sọ pé owó wà fún ẹni tó bá ja ìjọba lólè
Àwọn ọlọ́pàá ti ṣe ìlérí pé, ẹni tó bá ja ìjọba lólè yóò gba owó tabua
1
yo
Àdìmúlà jẹ oúnjẹ tó pọ̀ níbi ìgbéyàwó tí a lọ lánàá
Ṣébí ẹ̀wà méjì péré ni Àdìmúlà jẹ níbi ìgbéyàwó tí a lọ lánàá
Àjẹfẹ̀-fun-fẹ̀yà ni Àdìmúlà jẹ níbi ìgbéyàwó tí a lọ lánàá
1
yo
Àdìmúlà jẹ oúnjẹ tó pọ̀ níbi ìgbéyàwó tí a lọ lánàá
Àdìmúlà ò jẹun púpọ níbi ìgbéyàwó tí a lọ lánàá
Àdìmúlà jẹ oúnjẹ díẹ̀ níbi ìgbéyàwó tí a lọ lánàá
0
yo
Morẹ́nikéjì ti ń rìn kiri láti àárọ̀
Morẹ́nikéjì ò lè jẹ adìyẹ
Morẹ́nikéjì ti ń jẹsẹ̀ adìyẹ kiri láti àárọ̀
0
yo
Morẹ́nikéjì ti ń rìn kiri láti àárọ̀
Morẹ́nikéjì ò lè jẹ adìyẹ
Morẹ́nikéjì ò mọ bí wọn ṣe jẹ ẹṣẹ adìyẹ
1
yo
Ọmọ yìí ti ń ṣìnà/Ọmọ yìí ti ń rin ìrìnkurìn
Ọmọ yìí fẹ́ lọ sùn sí inú igbó
Ọmọ yìí tí ń wọgbọ́ atú lọ láti ìgbà tó tí ń bá àwọn ọ̀rẹ́ burúkú rìn
1
yo
Ọmọ yìí ti ń ṣìnà/Ọmọ yìí ti ń rin ìrìnkurìn
Ọmọ yìí fẹ́ lọ sùn sí inú igbó
Ọmọ yìí tí ri ọ̀nà àbáyọ láti ìgbà tó tí ń bá àwọn ọ̀rẹ́ tuntun rìn
0
yo
Àwọn ọlọ́pàá ti sọ fún ìjọba kí wọ́n ṣe sùúrù
Ìjọba ti gbé ìgbésẹ̀ lóri ọ̀rọ̀ àwọn ọlọ́pàá yìí
Àwọn ọlọ́pàá ti sọ fún ìjọba kí wọ́n ya fẹ̀dọ̀ lẹ́rí òróǹró lóri ọ̀rọ̀ yìí
0
yo
Àwọn ọlọ́pàá ti sọ fún ìjọba kí wọ́n ṣe sùúrù
Ìjọba ti gbé ìgbésẹ̀ lóri ọ̀rọ̀ àwọn ọlọ́pàá yìí
Àwọn ọlọ́pàá ti sọ fún ìjọba kí wọ́n pa gbogbo àwọn ẹlẹ́wọn
1
yo
Wọ́n mọ ibi tó sápamọ́ sí
Wọ́n mọ ibi tó ti lọ yàgbẹ́
Àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mọ ibi tí ó faraṣoko sí
0
yo
Wọ́n mọ ibi tó sápamọ́ sí
Wọ́n mọ ibi tó ti lọ yàgbẹ́
Àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mọ bí ó ṣe jí iṣu lóko
1
yo
Kó sọ òótọ́ ọ̀rọ́ fún wa
Kó la ahọ́n rẹ̀ kalẹ̀
Dérelé má ń fi ọ̀rọ̀ sábẹ́ ahọ́n fún wa
1
yo
Kó sọ òótọ́ ọ̀rọ́ fún wa
Kó la ahọ́n rẹ̀ kalẹ̀
Dérelé má ń sọ ọ̀ọ́tọ́ ọ̀rọ̀
0
yo
Ajíkòbí gbádùn gan/ Ajíkòbí jayé gan
Ajíkòbí ti wọ inú ọkọ̀
Ajíkòbí jayé bí i ẹni tí kò ní kú mọ́
0
yo
Ajíkòbí gbádùn gan/ Ajíkòbí jayé gan
Ajíkòbí ti wọ inú ọkọ̀
Ajíkòbí kò jayé tó fi kú
1
yo
Wọn ti tú àṣírí ọ̀rọ̀ tó ṣẹlẹ̀ láàárín àlùfáà àti ọmọbìnrin kan
Wọn ò sọ bí ọ̀rọ̀ náà ṣe jẹ́
Wọ́n ti bọ́ṣọ lóju eégún lóri ọ̀rọ̀ tó ṣẹlẹ̀ láàárín àlùfáà àti ọmọbìnrin kan
0
yo
Wọn ti tú àṣírí ọ̀rọ̀ tó ṣẹlẹ̀ láàárín àlùfáà àti ọmọbìnrin kan
Wọn ò sọ bí ọ̀rọ̀ náà ṣe jẹ́
Wọ́n parọ́ ọ̀rọ̀ tó ṣẹlẹ̀ láàárín àlùfáà àti ọmọbìnrin náà
1
yo
Alóńgẹ́ ti sọ ọ̀rọ̀ náà bó ṣe jẹ́
Alóńgẹ́ kì í jẹun púpọ̀
Alóńgẹ́ ti sọ ojú abẹ ọ̀rọ̀ náà níkòó
0
yo
Alóńgẹ́ ti sọ ọ̀rọ̀ náà bó ṣe jẹ́
Alóńgẹ́ kì í jẹun púpọ̀
Alóńgẹ́ kò sọ ojú abẹ ọ̀rọ̀ náà níkòó
1
yo
Wà á bí ọkùnrin, wà á bí obìnrin
O ò ní bímọ
Wà á bísun, wà á bí ìwàlẹ̀ láṣẹ Èdùnmàrè
0
yo
Wà á bí ọkùnrin, wà á bí obìnrin
O ò ní bímọ
O ò ní bísun, O ò ní bí ìwàlẹ̀ láṣẹ Èdùnmàrè
1
yo
Àkànní ti kú
Àkànní wà láàyè
Àkànní ti rèwàlẹ̀ àsà
1
yo
Àkànní ti kú
Àkànní wà láàyè
Àkànní ti ra ọkọ̀ tuntun
0
yo
Àlàdé sọ ọ̀rọ̀ jáde láìbẹ̀rù
Àlàdé ń bẹ̀rù láti sọ̀rọ̀
Àlàdé la ọ̀rọ̀ mọ́lẹ̀
0
yo
Àlàdé sọ ọ̀rọ̀ jáde láìbẹ̀rù
Àlàdé ń bẹ̀rù láti sọ̀rọ̀
Àlàdé fòyà láti la ọ̀rọ̀ náà mọ́lẹ̀
1
yo
Ó kọ̀ láti gbọ́rọ̀ sí bàbá rẹ̀ lẹ́nu
Ọ gbọ́rọ̀ sí bàbá rẹ̀ lẹ́nu
Ó kọtí ikún sí ọ̀rọ̀ bàbá rẹ̀
1
yo
Ó kọ̀ láti gbọ́rọ̀ sí bàbá rẹ̀ lẹ́nu
Ọ gbọ́rọ̀ sí bàbá rẹ̀ lẹ́nu
Ó tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ bàbá rẹ̀
0
yo
Ó jẹ ìyà
Ó jẹ̀gbádùn
Ó pàpà rí yà he
1
yo
Ó jẹ ìyà
Ó jẹ̀gbádùn
Ó pàpà jayé tó wáyé wá jẹ
0
yo
Àlàbí jẹ ìyà púpọ̀
Àlàbí jẹ ìgbádùn púpọ̀
Àlàbí gbóòórùn ara rẹ̀
1
yo
Àlàbí jẹ ìyà púpọ̀
Àlàbí jẹ ìgbádùn púpọ̀
Àlàbí ti lọ jayé ọba
0
yo
Adélaní ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìbínú
Àlàbí ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́
Adélaní ń tu bí ejò
1
yo
Adélaní ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìbínú
Àlàbí ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́
Adélaní ń tu pẹ̀lú sùúrù
0
yo
Àwọn Olúwálé bínú gidigidi
Àwọn Olúwálé jẹ oúnjẹ
Àwọn Olúwálé gbaná jẹ
1
yo
Àwọn Olúwálé bínú gidigidi
Àwọn Olúwálé jẹ oúnjẹ
Àwọn Olúwálé jẹ ìrẹsì tí wọ́n sè
0
yo
Ó lagídí lórí ọ̀rọ̀ náà
Ó fara balẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà
Ó gba ọ̀rọ̀ náà sórí
1
yo
Ó lagídí lórí ọ̀rọ̀ náà
Ó fara balẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà
Ó yin ọ̀rọ̀ náà nù
0
yo
Olùkọ́ ti ẹni tí kò ní ohunkóhun mọ́
Olùkọ́ ti di ẹni tí ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀
Olùkọ́ ti dẹni ilẹ̀
1
yo
Olùkọ́ ti ẹni tí kò ní ohunkóhun mọ́
Olùkọ́ ti di ẹni tí ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀
Olùkọ́ ti dẹni òkè
0
yo
Mi ò lè fara mọ́ ọn mọ́
Mo lè gbà á mọ́ra
Mo ti sún kàngiri
1
yo
Mi ò lè fara mọ́ ọn mọ́
Mo lè gbà á mọ́ra
Mo rára gbà á sí
0
yo
Obìnrin oníjàgídíjàgan
Obìnrin oníwà tútù
Pamínkú obìnrin ni ọ́
1
yo
Obìnrin oníjàgídíjàgan
Obìnrin oníwà tútù
Obìnrin ni ìwà ire
0
yo
Ọlá ń gbádùn
Ọlá ń jẹ ìyà
Ọlá ń jẹ tinu ẹyin
0
yo
Ọlá ń gbádùn
Ọlá ń jẹ ìyà
Ọlá ń mu gaàrí
1
yo
Adé ń jàmí níyàn
Adé ń gbọ́ tèmi
Adé ń lọ́yà mi
1
yo
Adé ń jàmí níyàn
Adé ń gbọ́ tèmi
Adé ti tẹtí sí ọ̀rọ̀ náà
0
yo
Ẹ ṣá máa gbádùn
Ẹ ṣáa máa jìyà
Ẹ ṣá máa mìlíkì
0
yo
Ẹ ṣá máa gbádùn
Ẹ ṣáa máa jìyà
Ẹ sá máa fòòró
1
yo
Ọmọdé tí ó bá mọ ìwàá wù, á súnmọ́ àwọn àgbà
Ọmọdé tí ó bá mọ ìwàá wù á jìnà sí àwọn àgbà
Ọmọdé tí ó bá mọ ọwọ́ wẹ̀ á bá àgbà jẹun
0
yo
Ọmọdé tí ó bá mọ ìwàá wù, á súnmọ́ àwọn àgbà
Ọmọdé tí ó bá mọ ìwàá wù á jìnà sí àwọn àgbà
Ọmọdé náà ò mọ ọwọ́ wẹ̀
1
yo
Òjó ń ṣiṣẹ́ kárakára
Òjó ń ọ̀lẹ
Òjó ń ṣiṣẹ́ bí eerin
0
yo
Òjó ń ṣiṣẹ́ kárakára
Òjó ń ọ̀lẹ
Òjó ń ṣiṣẹ́ bí ìjàpá
1
yo
Afúni níṣẹ́ tí kò ní sérè níbẹ̀
Afúni níṣẹ́ elérè tabua
Afúni lóko ìdí ọ̀pẹ ro
1
yo
Afúni níṣẹ́ tí kò ní sérè níbẹ̀
Afúni níṣẹ́ elérè tabua
Afúni lóko etídò ro
0
yo
Ó rán an iṣẹ́ tí ó léwu
Ó rán an níṣẹ́ tó nì ààbò
Ó rá an níṣẹ́ dé tòrutòru
1
yo
Ó rán an iṣẹ́ tí ó léwu
Ó rán an níṣẹ́ tó nì ààbò
Ó rá an níṣẹ́ dé ọlà
0
yo
Ó ń pariwo
Ó dákẹ́ jẹ́
Ó ń lọọgun tantan
1
yo
Ó ń pariwo
Ó dákẹ́ jẹ́
Ó dákẹ́ sii
0
yo
Táyé máa ń lu àwọn oníbàárà rẹ̀ ní jìbìtì
Táyé jẹ́ olóòótọ́ sí àwọn oníbàárà rẹ̀
Táyé máa ń dé àwọn oníbàárà rẹ̀ mọ́lẹ̀
1
yo
Táyé máa ń lu àwọn oníbàárà rẹ̀ ní jìbìtì
Táyé jẹ́ olóòótọ́ sí àwọn oníbàárà rẹ̀
Táyé máa wín àwọn oníbàárà rẹ̀
0
yo
Ó fajúro
Ó túraká
Ó kárí bọnú
1
yo
Ó fajúro
Ó túraká
Ó fò kiri
0
yo
O ó jẹ ìyà tó pọ̀
O ó jẹ ìgbádùn tó pọ̀
O ó fẹnu fẹ́ra bí abẹ̀bẹ̀
1
yo
O ó jẹ ìyà tó pọ̀
O ó jẹ ìgbádùn tó pọ̀
O ó pọ́nnu lá bí ẹni jẹ wàrà
0
yo
Àjàdí rí ìbínú àwọn tó jù ú lọ
Àjàdí rí ìyọ́nú àwọn tó jù ú lọ
Àjàdí tẹ aṣọ àgbà mọ́lẹ̀
1
yo
Àjàdí rí ìbínú àwọn tó jù ú lọ
Àjàdí rí ìyọ́nú àwọn tó jù ú lọ
Àwọn àgbà ti ṣàdúrà fún Àjàdí
0
yo
Ènìyàn súnmọ́ni kò sọ pé kó ṣeni láàánú
Ènìyàn súnmọ́ni lè fa kó ṣeni láàánú
Àjùmọ̀bí ò kan tàánú
1
yo
Ènìyàn súnmọ́ni kò sọ pé kó ṣeni láàánú
Ènìyàn súnmọ́ni lè fa kó ṣeni láàánú
Àjùmọ̀bí lè ṣe ni láàánú
0
yo
Ènìyàn ẹni náà ló lè kó àbùkù bá ẹni
Ènìyàn ẹni náà ló lè kó ọlá bá ẹni
Iṣu ẹni ló ń tọwọ̀ ẹni bọ epo
1
yo
Ènìyàn ẹni náà ló lè kó àbùkù bá ẹni
Ènìyàn ẹni náà ló lè kó ọlá bá ẹni
A kì í báni tan, ká fani nítan ya
0
yo
Alákòóbá
Onígbọ̀wọ́
Oníyangí
1
yo
Alákòóbá
Onígbọ̀wọ́
Olóore
0
yo
Òjó wá àkóbá fún ara rẹ̀
Òjó ò wá àkóbá fún ara rẹ̀
Òjó gbá ṣọṣọ lójú
1
yo
Òjó wá àkóbá fún ara rẹ̀
Òjó ò wá àkóbá fún ara rẹ̀
Òjó yàgò fún ṣọṣọ
0
yo
Ohun burúkú má ṣẹlẹ̀ síni
Ohun rere kó ṣẹlẹ̀ síni
Igi gogoro má gún mi ojú
1
yo
Ohun burúkú má ṣẹlẹ̀ síni
Ohun rere kó ṣẹlẹ̀ síni
Igi gogoro kò lè gún mi ojú
0
yo
Ayé ìjẹkújẹ ni Àwẹ̀lé ń jẹ
Ayé ìwọ̀ntuwọ̀nsì Àwẹ̀lé ń jẹ
Ayé fàmílétè n tutọ́ ni Àwẹ̀lé ń jẹ
1
yo
Ayé ìjẹkújẹ ni Àwẹ̀lé ń jẹ
Ayé ìwọ̀ntuwọ̀nsì Àwẹ̀lé ń jẹ
Ayé ìwọ̀ntún ìwọ̀n òsì ni Àwẹ̀lé ń jẹ
0
yo
Ọ̀lẹ tí kì í ṣiṣẹ́
Ènìyàn tí ó ṣiṣẹ́ kárakára
Ajínasẹ̀
1
yo
Ọ̀lẹ tí kì í ṣiṣẹ́
Ènìyàn tí ó ṣiṣẹ́ kárakára
Ají́gbọ́nini
0
yo
Ènìyàn tí kò bí ju ọmọ kan lọ kò yàtọ̀ sí ènìyàn tí kò bí rárá
Ènìyàn tí ó bí ọmọ púpọ̀ yàtọ̀ sí ènìyàn tí kò bí rárá
Ọlọ́mọ kan kò kúrò lágàn
1
yo
Ènìyàn tí kò bí ju ọmọ kan lọ kò yàtọ̀ sí ènìyàn tí kò bí rárá
Ènìyàn tí ó bí ọmọ púpọ̀ yàtọ̀ sí ènìyàn tí kò bí rárá
Ọlọ́́mọ kan kúrò ní kị lo bí?
0
yo
Ènìyàn kì í ṣe ohun tí kò dára fún àwọn tí ó yíi ká
Ènìyàn kì í ṣe ohun tí ó bàjẹ́ sí àwọn tí ó yí i ká
A kì í sumí rírọ̀ sí tòsí
0
yo
Ènìyàn kì í ṣe ohun tí kò dára fún àwọn tí ó yíi ká
Ènìyàn kì í ṣe ohun tí ó bàjẹ́ sí àwọn tí ó yí i ká
Ilé là ń tẹ̀kọ rírọ̀ sí
1
yo
Ọ̀rọ̀ yìí kò kàn rí bẹ́ẹ̀ lásán
Ọ̀rọ̀ yìí kàn rí bẹ́ẹ̀ ni
Ejò lọ́wọ́ nínú ọ̀rọ̀ yìí
1
yo
Ọ̀rọ̀ yìí kò kàn rí bẹ́ẹ̀ lásán
Ọ̀rọ̀ yìí kàn rí bẹ́ẹ̀ ni
Àmúwá Ọlọ́run ni ọ̀rọ̀ náà
0
yo
Alágbára ni Àlàdí
Ọ̀lẹ ni Àjàdí
Àjànàkú ni Àjàní
0
yo
Alágbára ni Àlàdí
Ọ̀lẹ ni Àjàdí
Jẹgúdúgẹrá ni Àjàní
1
yo
Bàbá mi bínú gidigidi
Bàbá mi yọ́nú gidigidi
Bàbá mi fara ya
1
yo
Bàbá mi bínú gidigidi
Bàbá mi yọ́nú gidigidi
Bàbá mi ti fojú àánú wò mí
0
yo
Ilẹ̀ ti ń ṣú
Ilẹ̀ ti ń mọ́
Ọjọ́ ti ń rebi àná
0
yo
Ilẹ̀ ti ń ṣú
Ilẹ̀ ti ń mọ́
Ọjọ́ kọ̀ tí ì rẹbi àná
1
yo
Ó pàpà fara balẹ̀
Ó pàdà da gbogbo rẹ̀ rú
Ó pàpà bu omi sùúrù mu
0
yo
Ó pàpà fara balẹ̀
Ó pàdà da gbogbo rẹ̀ rú
Ó padà mu omi wàhálà
1
yo
A ó sọ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nípa ọ̀rọ̀ náà
A ó sọ́ ọ̀rọ̀ ná léréfèé
A ó tú iṣu dé ìsàlẹ̀ ìkòkò
0
yo
A ó sọ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nípa ọ̀rọ̀ náà
A ó sọ́ ọ̀rọ̀ ná léréfèé
A ó ré e lórí
1
yo
Olúwọlé kọ̀jálẹ̀
Olúwọlé gbà
Olúwọlé fárígá
1
yo
Olúwọlé kọ̀jálẹ̀
Olúwọlé gbà
Olúwọlé baralẹ̀
0
yo