|
sentence: Àwòrán àti ọ̀rọ̀ abẹ́ - àwòrán láti ọwọ́ọ Myo Min Soe / Irrawaddy náà ń bá Ohùn Àgbáyé ṣiṣẹ́ ìròyìn . Min <person> Soe <person> Irrawaddy <person> Ohùn <person> Àgbáyé <organization> |
|
sentence: Síbẹ̀síbẹ̀ , fún ìdáààbò àwọn ènìyàn , ṣíṣe ṣì kú . |
|
sentence: Ìfẹ̀hónúhàn náà |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Urban Study Group , ẹgbẹ́ aṣiṣẹ́ ọ̀fẹ́ - tí - kò - ní - èrè tí ó máa ń fi ààbò fún àwọn ohun àjogúnbá Dhaka Àtijọ́ fi ìwé ẹ̀dùn ìdáwọ́dúróo àdàwólulẹ̀ náà ránṣẹ́ sí àwọn tí ọ̀rán kàn , tí ó sì mẹ́nu ba àṣẹ Ilé - ẹjọ́ Gíga . Urban <person> Study <organization> Group <organization> Dhaka <organization> |
|
sentence: Àwọn dókítà méjì kan náà kú látàrí ibà - ẹ̀fọn , èyí sì ti ń mú kí àwọn ènìyàn ó máa bẹ̀rù . |
|
sentence: Àwọn àjogúnbá tí ó gbèèrú àti tí ó ní ìmúgbòrò ti di gbẹndẹ́kẹ : A ò kí ń ṣe òǹrorò , a ò kí ń ṣe oníjàgídíjàgan , a ò kí ń ṣe apanijẹ , a ò kàn kí ń ṣe ọ̀daràn àti ọmọ - ìta . |
|
sentence: Ìgbà wo ni a óò kọ́ ẹ̀kọ́ , tí a ó fi gbọ́n ? |
|
sentence: Obama ni wá , Garvey ni wa , Marley ni wa , Angelou ni wa , Walcott ni wa . |
|
sentence: Àwọn tí ó wá ṣiṣẹ́ náà sọ wípé olóríi àwọn , ọmọ ìgbìmọ̀ ìbílẹ̀ ( Dhaka - 7 ) Haji Md . Dhaka <organization> Md <person> |
|
sentence: Àwọn akọrin láti Kingston , Clarendon àti Spanish Town ń ṣiṣẹ́ pọ̀ lóríi ọ̀rọ̀ orin níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Ìfiṣẹ́ránṣẹ́ Àyípadà Ojú - ọjọ́ . Kingston <organization> Clarendon <organization> Spanish <organization> Town <location> |
|
sentence: Ohun tí ó lè fà á lè pọ̀ – ọ̀pọ̀ ni ó kó àìsàn ní ọdún tí ó kọjá , tí wọn kò fura . ọdún <location> |
|
sentence: Ojúṣe láti ṣe ìrántí : ọgbọ̀n ọdún lẹ́yìn Tiananmen ọgbọ̀n <location> Tiananmen <organization> |
|
sentence: Ẹ jẹ́ ká mọ̀ wípé ìyàsọ́tọ̀ọ̀tọ̀ nípa ti àwọ̀ ara ni ogún tí ó ń pín wa níyà [ … ] |
|
sentence: Àjọ Alágbèélébùú Pupa ní yóò tó ọmọ orílẹ̀ 2 , 700 tí wọ́n pa , àmọ́ àwọn mìíràn nípé ó jù bẹ́ẹ̀ lọ . Àjọ <person> Alágbèélébùú <organization> Pupa <organization> |
|
sentence: Àjogúnbá , ìtàn - ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìnwá , àṣá jẹ́ ọ̀rọ̀ tí kò já mọ́ nǹkan ní orílẹ̀ - èdè yìí ! |
|
sentence: Deng , tí a tún mọ̀ sí Huang Huang , tí ó jẹ́ ayàwòrán aládàádúró tí ó ti bá òǹyàwòrán Beijing , Ai Weiwei ṣiṣẹ́ papọ̀ . Huang <person> Beijing <organization> Weiwei <person> |
|
sentence: Pẹ̀lú ìdádúró ìrànlẹ́wọ̀n , àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ṣì wà lábẹ́ ìṣọ́ : |
|
sentence: Ọdún gorí ọdún , iṣẹ́ “ 1 . 5 túbọ̀ ń rinlẹ̀ sí i ní ìlà - oòrùn Caribbean , níbi tí àwọn ọ̀kọrin ti ṣe àlọ́pọ̀ ọ̀rọ̀ akéwì St . ìlà <organization> - <location> oòrùn <location> Caribbean <location> |
|
sentence: Òǹyàwòrán ọmọ bíbí Taiwan Shake ni aṣàgbékalẹ̀ , àwòrán Ọkùnrin Ọkọ̀ Ogun tí ó wà ní àárín gbùngùn - un Taipei ni ìmísí àgbékalẹ̀ náà . Taiwan <organization> àárín <organization> gbùngùn <location> - <location> un <location> Taipei <location> |
|
sentence: Ó rọrùn fún ẹgbẹ́ tí ó dúró ṣinṣin láti dá ètòo ẹlẹ́yàmẹyà àti ìtẹ̀bọlẹ̀ . |
|
sentence: Ọdún - un 2016 ni a ṣe ìgòo ọtí - líle náà , ìyẹn ní ìrántí ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n tí ìṣẹ̀lẹ̀ láabi ọjọ́ 4 oṣù Òkúdù wáyé . Ọdún <location> ọdún <location> ọjọ́ <location> |
|
sentence: Wo òkúta ìsàlẹ̀ òkun , wo ẹja bí ó ṣe kéré |
|
sentence: Ilé àjogúnbá náà di àwópalẹ̀ pẹ̀lú bí Ilé - ẹjọ́ Gíga ṣe pa àṣẹ . |
|
sentence: Ǹjẹ́ ìjọbá ń ṣe tó ? |
|
sentence: Wọ́n gba ẹ̀sìn àwọn babańláa wa , wọ́n mú ìgbàgbọ́ àti ohun iyìi wa kúrò ní ọkàn - an wa . |
|
sentence: Ragib Hassan ni ó ní àwòrán ní oríi Wikipedia . Hassan <person> Wikipedia <person> |
|
sentence: Síbẹ̀ , bí ìwé ìròyìn ṣe jábọ̀ , díẹ̀ lára àwọn ọmọ ìbílẹ̀ ń yọ̀ fún àdàwólulẹ̀ ilé náà . |
|
sentence: ( … ) Ìjọba rí i wípé ó tó àsìkò láti sún owó ìwé ẹ̀rí ọmọ - ìlú - fún - ìrìnnà , ó sì ti yọ ọwọ́ọ Kílàńkóo rẹ̀ kúrò nínú kíkó owó lé e lórí , kí ó ba lè ṣe , fún àpẹẹrẹ , pèsè omi , ináa mànàmáná àti àwọn ohun amáyérọrùn mìíràn . |
|
sentence: Àwọn kan tẹ̀lée padà sílé , wọ́n sì ya àwòrán nínú ilée wọn . |
|
sentence: A lò ó pẹlú àṣẹ . |
|
sentence: Àwọn alátakò ti sọ pé ó ṣe pàtàkì láti rántí wípé ìwé ẹ̀rí ọmọ - ìlú - fún - ìrìnnà dúró fún ìdánimọ̀ ọmọ ìlú ní òkè òkun , torí ìdí èyí , kò ṣe é yẹ̀ sílẹ̀ fún wọn . |
|
|