|
sentence: Aàfin Nimtali . Aàfin <organization> Nimtali <location> |
|
sentence: Gbogbo ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn wá jẹ́ ti òṣèlú torí ìdí èyí ó yẹ kí wọ́n ṣe àtúnṣe gẹ́gẹ́ bíi ọ̀rọ̀ òṣèlú . |
|
sentence: Ọlọ́pàáa Sichuan fi ọwọ́ọ ṣìgún òfin mú Deng ní ilée rẹ̀ ní Yibin ní ọjọ́ Ẹtì tí ó kọjá , lẹ́yìn wákàtí díẹ̀ tí ó ṣe àtúnpín àwòrán - an Twitter kan tí ó jẹ́ ti ìgò ọtí - líle 64 , gẹ́gẹ́ bí Iléeṣẹ́ - tí - kìí - ṣe - tìjọba , Adáààbòbo Ẹ̀tọ́ Ọmọ ènìyàn ti China ( CHRD ) . Sichuan <organization> Yibin <organization> ọjọ́ <location> wákàtí <location> Twitter <person> Adáààbòbo <person> Ẹ̀tọ́ <organization> Ọmọ <organization> ènìyàn <organization> ti <organization> China <organization> CHRD <person> |
|
sentence: A fi àṣẹ lò ó . |
|
sentence: OBS : Ìwé ìdánimọ̀ pélébé ( B . I ) wúlò gẹ́gẹ́ bí àmì ìdánimọ̀ ní àárín ìlú Angola . Angola <organization> |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Ilé - ẹjọ́ Gíga Dhaka ti fi àṣẹ pe Ọ̀gá Àgbà Ètò Ìlera ti ìjọba . Ilé <person> - <organization> ẹjọ́ <organization> Gíga <organization> Dhaka <organization> |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Àwòrán - an Emma Lewis , a lò ó pẹ̀lú àṣẹ . Lewis <person> |
|
sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Fernando Gomes , a gba àṣẹ láti lò ó . Gomes <person> |
|
sentence: Iṣẹ́ àtúnṣe sí àwọn àjogúnbá ìgbàa Mughal ní mọ́ṣálááṣí Bangshal Mukim Bazar Jam - e àti mọ́ṣálááṣí Siddique Bazar Jam - e ti di ohun ìgbàgbé nítorí ojú àpá ò le è jọ ojú ara , ó ti yàtọ̀ . mọ́ṣálááṣí <organization> Bangshal <location> Mukim <location> Bazar <location> Jam <location> - <location> e <location> mọ́ṣálááṣí <organization> Siddique <location> Bazar <location> Jam <location> - <location> e <location> |
|
sentence: Àwọn tó bá ara wọn ní ìsàlẹ̀ ní ìṣòro láti bá àwọn tí ó wà ní òkè ṣe . |
|
sentence: Akọ̀ròyìn Reuters méjì Wa Lone àti Kyaw Soe Oo rìnrìn òmìnira lẹ́yìn tí a dá wọn sílẹ̀ ní ẹ̀wọ̀n Insein ní Yangon . Reuters <person> Lone <person> Soe <person> Oo <person> ẹ̀wọ̀n <organization> Insein <location> Yangon <organization> |
|
sentence: Òǹkọ̀wé Tania Kamrun Nahar tan ìmọ́lẹ̀ sí ìdí tí kò fi yẹ kí ilé yìí di àdàwólulẹ̀ : Kamrun <person> Nahar <person> |
|
sentence: Trinidad àti Tobago jẹ́ àkọ́kọ́ nínú àwọn orílẹ̀ - èdè ní àgbáyé tí yóò ya ọjọ́ sọ́tọ̀ láti fi sọríi ìfòpin sí òwò ẹrú , àmọ́ lẹ́yìn - in 34 ọdún tí ìsinmi àpapọ̀ náà fi ẹsẹ̀múlẹ̀ àti ọdún 185 lẹ́yìn - in tí Àbá òfin Ìfòpin sówò - ẹrú kọ́kọ́ wáyé , awuyewuye ṣì ń lọ lóríi wípé bóyá erékùṣù - ìbejì Trinidad <organization> àti <location> Tobago <location> 34 <location> |
|
sentence: Ní àárín - in àjàkálẹ̀ náà , Alákòóso - ìlú Àríwá Dhaka ti fagilé ìsinmi ránpẹ́ àwọn ikọ̀ tí ó ń rí sí pàntí kíkó àti ìgbégidínà àpọ̀si ẹ̀fọn . Àríwá <organization> Dhaka <location> |
|
sentence: Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú ìwé ìròyìn Bangla Tribune , Dókítà Gulzar sọ wípé kò sí bí a ṣe lè wo ibà ẹ̀fọn yìí nígbà àkọ́kọ́ tó , kí ó máà tún ṣeni lẹ́ẹ̀ẹkejì . Bangla <person> Tribune <organization> |
|
sentence: Èyí jẹ́ ìrántí ohun tí ojú àwọn ọmọ Mozambique rí ní ìparí ọdún - un 2018 , nígbàtí ìjọba pinnu láti fi owó kún ìwé àṣẹ gbogbo , bẹ́ẹ̀ náà ni ó bá ìwé àṣẹ ọkọ̀ wíwà , tí ìdíyelée rẹ̀ fi ìdá 500 gbéwó lórí . Mozambique <organization> ìparí <location> |
|
sentence: Muntasir Mamun ti kọ àìmọye ìwé lóríi ìtàn - ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìnwá àti àjogúnbá ìlúu Dhaka . Mamun <person> Dhaka <organization> |
|
sentence: Èsì tí U Ye Ni fún àwọn ọmọ ajagun rè é : Ye <person> Ni <person> |
|
sentence: Ojú - ìwé Facebook ti BBC Bangla rọ àwọn òǹkàwée rẹ̀ láti jábọ̀ àwọn ìgbésẹ̀ akin tí àwọn òníṣẹ́ ìlú Dhaka ń gbé láti gbógun ti ẹ̀fọn . Facebook <person> BBC <person> Bangla <organization> Dhaka <organization> |
|
sentence: Wọ́n ò mọ̀ pé ilé náà ti di ẹgẹrẹmìtì , ó sì lè wò lulẹ̀ kí ó wó lù wọ́n — tí í ṣe àpẹẹrẹ àìmọ̀kanmọ̀kàn àwọn ènìyàn sí ìpamọ́ ohun àjogúnbá àti àtìlẹ́yìn fún àtúnṣe sí ilé àtijọ́ tí ó wà ní Bangladesh . Bangladesh <organization> |
|
sentence: Eré ìtàgé tí ó ní àkójọpọ̀ orin abínibí , ijó àti ewì ni a mọ Thangyat mọ́ . Thangyat <person> |
|
sentence: Ní tèmi , gbogbo ọ̀ràn yìí pátá yóò jẹ́ yíyẹ̀ lulẹ̀ bí a bá le è ṣe iṣẹ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ ti àtúnṣe sí ìwé òfin . |
|
sentence: Oríi Wikipedia ni àwòrán yìí wà . Wikipedia <person> |
|
sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Shakil Ahmed . Ahmed <person> |
|
sentence: Ajábọ̀ - ìròyín Arthur Dash gbóríyìn fún “ ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìnwá ìdàgbàsókè """" orílẹ̀ - èdè náà ní ti ọ̀ràn - an ẹ̀yà , àmọ́ ó tún dá àbá wípé ìṣòro náà ju bí àwọn ti ṣe rò lọ , ó sì mú u ní àbá pé ó yẹ kí ọ̀rọ̀ alákòóso ìlú jẹ́ ìwúrí fún ọmọìlú láti ṣe ìwádìí fínnífínní sí bí Dash <person> |
|
sentence: Ó sì ń fa àmì ìfòyà . |
|
sentence: Mo ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn aláṣẹ fún ogójì ọdún tí ó kọjá láti gba àwọn ilé àjogúnbá bíi Bara Katra àti Choto Katra sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tí ó fẹ́ pa ìtàn àtẹ̀yìnwá rẹ́ . ogójì <location> Bara <organization> Katra <location> Choto <organization> Katra <location> |
|
sentence: Ó kọ sínú ìwé ìròyìn ìbílẹ̀ẹ Bhorer Kagoj : Bhorer <person> Kagoj <organization> |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Àtẹ̀jáde ìtúmọ̀ 22 Òkúdù 2019 11 : 13 GMT 22 <location> |
|
|