|
sentence: Síbẹ̀ ojúṣe láti rántí kò dẹ́kun fífi ìmísí sí ọkàn àwọn ènìyàn àti àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè káàkiri àgbáyé . |
|
sentence: Ó rọrùn fún ẹgbẹ́ tí ó dúró ṣinṣin láti dá ètòo ẹlẹ́yàmẹyà àti ìtẹ̀bọlẹ̀ . |
|
sentence: Ìloro àbáwọlé ìwọ̀ - oòrùn - un ààfin náà nìkan ló ṣì ń dúró . |
|
sentence: Wọ́n ò mọ̀ pé ilé náà ti di ẹgẹrẹmìtì , ó sì lè wò lulẹ̀ kí ó wó lù wọ́n — tí í ṣe àpẹẹrẹ àìmọ̀kanmọ̀kàn àwọn ènìyàn sí ìpamọ́ ohun àjogúnbá àti àtìlẹ́yìn fún àtúnṣe sí ilé àtijọ́ tí ó wà ní Bangladesh . Bangladesh <organization> |
|
sentence: Àjogúnbá Ìṣẹ̀lẹ̀ Àtẹ̀yìnwá — ọ̀rọ̀ tí ò jẹ́ mọ́ nǹkan |
|
sentence: Bákan náà àwọn alátìlẹ́yìn AL sọ wípé ilé àtijọ́ náà kò sí lóríi àwọn ibi àjogúnbá tí ó wà nínú àkọsílẹ̀ . |
|
sentence: Ẹ̀ka ológun Agbègbè Yangon kọ ìwé ẹ̀sùn - un ìbanilórúkọjẹ́ sí olóòtú èdèe - Burmese U Ye Ni wípé ibùdó - ìtakùn - àgbáyé akọ̀ròyìn náà gbè lẹ́yìn ẹnìkan nínú ìròyìn ìkọlù láàárín - in ọmọ - ogun ìjọba àti àwọn adárúgúdù sílẹ̀ Ọmọ ogun Arakan ní Ìpínlẹ̀ Rakhine tí ó tẹ̀ jáde . Yangon <organization> Ye <person> Ni <person> Arakan <organization> Rakhine <organization> |
|
sentence: Bí a ti ṣe ń pe “ wine """" ní èdèe Putonghua náà ni à ń pe “ 9 """" . |
|
sentence: Ibà - ẹ̀fọn ti ọdún yìí jẹ́ tuntun , ó sì yára pa ènìyàn . ọdún <location> |
|
sentence: Ilé àjogúnbá náà di àwópalẹ̀ pẹ̀lú bí Ilé - ẹjọ́ Gíga ṣe pa àṣẹ . |
|
sentence: Àjùsẹ́wọ̀n fún yẹ̀yẹ́ |
|
sentence: A máa wà ní ojú òpópónà ní olú ìlú fún oṣù Èrèlé , ní àwọn ọjọ́ kọ̀ọ̀kan tí a yàn , ọjọ́ kẹrin oṣù Èrèlé ni ìwọ́de náà bẹ̀rẹ̀ , àmọ́ ní ọjọ́ kéje ni a máa padà sí ojú òpópónà , tí a óò tún wà ní ọjọ́ kankànlá , tí a ó sì jábọ̀ ní ọjọ́ kẹtàlá , bí ìjọba kò bá yí ohùn padà . oṣù <location> ọjọ́ <location> ọjọ́ <location> ọjọ́ <location> ọjọ́ <location> |
|
sentence: Ọnà ara ilé náà kọjá àfẹnusọ tí a kò le è rí lára àwọn ilé mìíràn ní àwọn agbègbè àtijọ́ọ Dhaka . Dhaka <organization> |
|
sentence: Iléeṣẹ́ náà ti yege nínúu ìtànká àwọn ìkéde tí ó ṣe kókó nípasẹ̀ẹ iṣẹ́ Ohùn fún Àyípadà Ojú - ọjọ́ . |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Orúkọ tí a pe ọtí - líle náà ni “ 8 wine 64 ″ . |
|
sentence: Ìròyìn nípa àjàkálẹ̀ àìsàn yìí ń gba gbogbo orí ẹrọ - alátagbà kan tí ó sì ń mú àìbalẹ̀ara àti ọkàn bá ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òǹlo ẹ̀rọ - alátagbà . |
|
sentence: Èyí [ ni ọ̀nà kan ] fún ìpèsí àkíyèsí ìjọba João Lourenço , wípé àfilé ìdíyelé kò yẹ nírú àsìkò yìí , nítorí owó náà ti ṣe gegere ju fún àwọn ọmọ ìlú . Lourenço <person> |
|
sentence: Ẹgbẹ́ Olóṣèlú The Communist Party ti China kò fi ìgbà kan sọ ọ́ ní gbangba rí wípé òún mọ̀ wípé ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí ṣẹ̀ tàbí ṣe ìwádìí fínnífínní síwájú sí i . The <person> Communist <organization> Party <organization> ti <organization> China <organization> |
|
sentence: Àtẹ̀jáde ìtúmọ̀ 22 Òkúdù 2019 11 : 13 GMT 22 <location> |
|
sentence: A fi ọwọ́ọ ṣìnkún òfin mú àwọn ọmọkùnrin orílẹ̀ èdèe China mẹ́rin , Fu Hailu , Zhang Jinyong , Luo Fuyu àti Chen Bing , ní ọdún - un 2016 fún ìṣẹ̀lẹ̀ ìgò ọtí - líle tí a sì fi ẹ̀sùn - un “ rírú ìṣẹ́po agbáraiìlú sókè """" . China <organization> Hailu <person> Jinyong <person> Fuyu <person> Bing <person> ọdún <location> |
|
sentence: Apá kan lára àwọn ilé àwòṣífìlà tí ó wà ní Sutrapur kò ṣe é rí mọ́n . Sutrapur <organization> |
|
sentence: Gbá iyìi rẹ̀ mú , àṣàà rẹ , àti ìdánimọ̀ọ rẹ . |
|
sentence: Agbẹnusọ fún Ẹ̀ka Ìjọba tí ó ń ṣe àbójútó ètò ìforúkọsílẹ̀ , Valdemar José , sọ fún àwọn akọ̀ròyìn ìbílẹ̀ Angola pé ìdíyelé fún ìwé ìrìnnà ìwọ̀lú lásán - làsàn lọ sí òkè nítorí owó gegere ni ó ń jẹ láti ṣe ìwé náà : Ẹ̀ka <person> Ìjọba <organization> tí <organization> ó <organization> ń <organization> ṣe <organization> àbójútó <organization> ètò <organization> ìforúkọsílẹ̀ <organization> José <person> Angola <organization> |
|
sentence: Trinidad àti Tobago jẹ́ àkọ́kọ́ nínú àwọn orílẹ̀ - èdè ní àgbáyé tí yóò ya ọjọ́ sọ́tọ̀ láti fi sọríi ìfòpin sí òwò ẹrú , àmọ́ lẹ́yìn - in 34 ọdún tí ìsinmi àpapọ̀ náà fi ẹsẹ̀múlẹ̀ àti ọdún 185 lẹ́yìn - in tí Àbá òfin Ìfòpin sówò - ẹrú kọ́kọ́ wáyé , awuyewuye ṣì ń lọ lóríi wípé bóyá erékùṣù - ìbejì Trinidad <organization> àti <location> Tobago <location> 34 <location> |
|
sentence: Jahaj Bari wà nínú àwọn ilé àkọ́pọ̀ Waqf ( mortmain ) tí kò ṣe é tà . Bari <person> Waqf <person> |
|
sentence: Irú ìpalẹ́numọ́ onísànánjúpa Beijing báwọ̀nyí ti ń kárí ayé , títí kan Hong Kong . Beijing <organization> Hong <organization> Kong <location> |
|
sentence: Ohun èlò fún ìwé ẹ̀rí ọmọ - ìlú - fún - ìrìnnà máa ń gbọ́n owó mì , nítorí iṣẹ́ ìdáàbòbò oríi rẹ̀ , tí àjọ ọba ń kówó lé lórí tẹ́lẹ̀ kí ó tó di ìgbà yìí . |
|
sentence: Bí àwọn iléeṣẹ́ ṣe ń ṣiṣẹ́ , ìyá ń ké . |
|
sentence: Àkọpamọ́ kan tí ó jẹ́ ti ìjọba US jábọ̀ ní ọdún - un 2014 wípé àyẹ̀wò tí ó wáyé nínú China sọ wípé yóò fẹ́rẹ̀ẹ́ tó ọmọ orílẹ̀ 10 , 454 tí wọ́n pa . ìjọba <person> US <organization> ọdún <location> China <organization> |
|
sentence: Níbẹ̀ , wọ́n fi ẹ̀kọ́ kún ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìtàkùrọ̀sọ àti kọ́ nípa ipa àyípadà ojú - ọjọ́ . |
|
sentence: Àwọn òǹlò ẹ̀rọ - alátagbà sọ ti wọn . |
|
|