|
sentence: Àwọn tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣe ojúu wọn fọ ohun tí ó ń gbé wọn lọ́kàn síta nínú ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ , bí àwọn akọni òǹkọ̀ròyìn ní Hong Kong ṣe ń kọ ìròyìn nípa ọjọ́ 4 oṣù Òkúdù . Hong <organization> Kong <location> ọjọ́ <location> |
|
sentence: Àwọn kan tẹ̀lée padà sílé , wọ́n sì ya àwòrán nínú ilée wọn . |
|
sentence: Bí omi - dídì ilé ayé ṣe ń yọ́ , òkun ń kún . |
|
sentence: Òun ni ibùgbé Gómìnà Dhaka ní ayée Ìjọba Mughal . Dhaka <organization> Ìjọba <person> Mughal <organization> |
|
sentence: Òǹyàwòrán ọmọ bíbí Taiwan Shake ni aṣàgbékalẹ̀ , àwòrán Ọkùnrin Ọkọ̀ Ogun tí ó wà ní àárín gbùngùn - un Taipei ni ìmísí àgbékalẹ̀ náà . Taiwan <organization> àárín <organization> gbùngùn <location> - <location> un <location> Taipei <location> |
|
sentence: Shuvra Kar kọ sí oríi Facebook : Kar <person> Facebook <person> |
|
sentence: Lọ́dọọdún , àwọn aláṣẹ China fi ọwọ́ agbára mú ìrántí ìṣẹ̀lẹ̀ náà , tí wọ́n sì fi àwọn agbọ̀rọ̀dùn sí àtìmọ́lé . China <organization> |
|
sentence: ẹlẹ́yàmẹyà nínú ilé - iṣẹ ṣe ń pín àwọn ènìyàn sọ́tọ̀ọ̀tọ̀ . |
|
sentence: Ohùn Àgbáyé ti ń jábọ̀ ìròyìn lórí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí fún ọdún mẹ́wàá . Ohùn <person> Àgbáyé <organization> ọdún <location> |
|
sentence: Níṣe ni Hong Kong kún fún àwòrán ìdánimọ̀ ẹgbẹ́ náà , òrìṣà abo ti Àwaarawa ní ìta gbangba . Hong <organization> Kong <location> |
|
sentence: Gbogbo ètò ni ó ní òṣùwọ̀n , tí ó ṣì jìnà gbégbérégbé sí òkè . |
|
sentence: Irrawaddy Náà sọ wípé òun kò ṣe àṣemáṣe ju jíjábọ̀ọ ìwọ̀yáàjà tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní sàkání náà láti ìbẹ̀rẹ̀ ọdún - un 2019 . Irrawaddy <person> ọdún <location> |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Àwọn tí kò bá ètò náà lọ yóò di aláìṣetó tí wọ́n á sì di ẹni àgbésẹ́yìn sí ipò kejì tàbí èyí tí ó burú ju bẹ́ẹ̀ lọ . |
|
sentence: Kedere ni ohùn ń jáde láti inú ilé àpérò ìlú - mọ̀ńká United Nations Conference ní Paris ( COP21 ) lọ́dún - un 2015 . United <person> Nations <organization> Paris <organization> lọ́dún <location> |
|
sentence: Eré ìtàgé tí ó ní àkójọpọ̀ orin abínibí , ijó àti ewì ni a mọ Thangyat mọ́ . Thangyat <person> |
|
sentence: Ní àfikún , ìjọba ti pín iye owó irúfẹ́ ìrìnàjò tí ó wà sí ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ , ó tò ó ní ẹsẹẹsẹ . |
|
sentence: Ní ayé òde òní tí ẹ̀rọ ayélujára mú iṣẹ́ ìwádìí rọrùn , ó yẹ kí o ṣe àyẹ̀wò sí ìgbàgbọ́ àwọn babańláa wa , ìbọ̀wọ̀ àti ìmọrírì àgbà , gbígba ìwùsàsí ẹni [ … ] ìtẹnumọ́ ẹwùn àti èrè ìwà ẹni , ìgbàgbọ́ ń bẹ nínú ẹbí , nínúu mọ̀lẹ́bí , nínú ìletò , nínúu àdúgbó . |
|
sentence: Ọdún gorí ọdún , iṣẹ́ “ 1 . 5 túbọ̀ ń rinlẹ̀ sí i ní ìlà - oòrùn Caribbean , níbi tí àwọn ọ̀kọrin ti ṣe àlọ́pọ̀ ọ̀rọ̀ akéwì St . ìlà <organization> - <location> oòrùn <location> Caribbean <location> |
|
sentence: Ó jẹ́ nǹkan ìbànújẹ́ wípé ilé náà ti ṣe tán , ó lè wó nígbàkigbà látorí àìṣàtúnṣe , àìkáràmáìsìkí ohun àjogúnbá , àti ìbàjẹ́ tí àwọn tí ó gbé ilé láì gba àṣẹ ń fà . |
|
sentence: Àwọn ìgòo Baijiu ń ṣe ìrántí ìpànìyànnípakúpa Tiananmen náà . Tiananmen <organization> |
|
sentence: Gẹ́gẹ́ bí alákòóso Bangladesh Waqf Administratioń ṣe sọ , gbígba àṣẹ pọn dandan láti gbé iṣẹ́ sílẹ̀ , tà tàbí ṣe àtúnṣe sí ohunkóhun tí ó bá jẹ́ ti Waqf . Bangladesh <person> Waqf <organization> Administratioń <organization> Waqf <person> |
|
sentence: Òǹlò Facebook Adrian Raymond sọ : Facebook <person> Raymond <person> |
|
sentence: Ìyá Ilẹ̀ - ayé ń ké tantan |
|
sentence: Wàhálà àyípadà ojú - ọjọ́ ní ọdún - un 2019 jẹ́ ohun tí ó nílò àbójútó kíákíá ju ti ìdúnrin lọ , àti ní Jamaica , àwọn ará ìgbèríko tí ó jẹ́ àgbẹ̀ , àwọn apẹja ń gbọ́ ìpè itanijí yìí . ọdún <location> Jamaica <organization> |
|
sentence: Pẹ̀lú ìfilọ́lẹ̀ẹ Panos fún àkòrí orin tuntun fún Caribbean fún Àyájọ́ Ilẹ̀ - ayé , ẹgbẹ́ẹ Jamaica náà ti ṣe tán láti ṣe eré ní iléèwé àti ní àdúgbò , láì yọ Kàwé Jákèjádò Jamaica sílẹ̀ àti iṣẹ́ igi gbíngbìn . Caribbean <organization> Jamaica <organization> Jamaica <organization> |
|
sentence: Ẹ̀gbẹ́ alájòótà yìí ti tasẹ̀ àgẹ̀rẹ̀ sí òfin abala 505 ( a ) tí ó ní wípé ọ̀daràn ni ẹni tí ó bá polongo ọ̀rọ̀ , àyesọ , tàbí jábọ̀ irúu rẹ̀ pẹ̀lú èrò láti mú kí ikọ̀ ajagun ó máà ka ojúṣe rẹ̀ kún tàbí kùnà láti ṣe ojúṣee rẹ̀ . |
|
sentence: Ní ọjọ́ kẹrin oṣù Èrèlé , Global Voices bá Fernando Gomes , ajìjàǹgbara ọmọ orílẹ̀ èdè Angola tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn alátìlẹ́yìn ìfẹ̀hónúhàn náà tàkùrọ̀sọ , láti mọ ohun gbogbo tí ó rọ̀ mọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ náà . ọjọ́ <location> Global <person> Voices <organization> Gomes <person> Angola <organization> |
|
sentence: Ọdún - un 1610 ni Dhaka di olú - ìlúu Bengal , ìyẹn ogójì ọdún sẹ́yìn . Ọdún <location> Dhaka <organization> Bengal <organization> ogójì <location> |
|
sentence: Ragib Hassan ni ó ní àwòrán ní oríi Wikipedia . Hassan <person> Wikipedia <person> |
|
sentence: Ọ̀kan lára ẹni tí a fi ẹ̀sùn kàn , Zeyar Lwin , sọ pé : Lwin <person> |
|
|