|
sentence: Ní ọjọ́ yẹn , ikọ̀ ogun orílẹ̀ - èdè China ṣíná bolẹ̀ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó ń ṣe ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn àtúnṣe ètò ìjọba àwaarawa . ọjọ́ <location> ikọ̀ <person> ogun <organization> orílẹ̀ <organization> - <organization> èdè <organization> China <organization> |
|
sentence: Àwòrán ìsàlẹ̀ yìí ni àwọn ilé àjogúnbáa Bangladeshi tí àdàwólulẹ̀ ń bá : Bangladeshi <organization> |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Ohùn Àgbáyé ti ń jábọ̀ ìròyìn lórí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí fún ọdún mẹ́wàá . Ohùn <person> Àgbáyé <organization> ọdún <location> |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Ilé yìí ṣì ń dúró lónìí . |
|
sentence: Ìfọwọ́ọ ṣìnkún òfin múni nítorí àtúnpín túwíìtì |
|
sentence: Ní ìpalẹ̀mọ́ ìsààmì ọgbọ̀n ọdún tí ìṣẹ̀lẹ̀ ọjọ́ 4 , ayàwòrán eré orí ìtàgé Deng Chuabin ti di ẹni tí ọ̀rọ̀ ìgò ọtí - líle 64 ń dá sẹ̀ríà fún lọ́wọ́lọ́wọ́ . ọgbọ̀n <location> ọjọ́ <location> Chuabin <person> |
|
sentence: Lọ́dọọdún , àwọn aláṣẹ China fi ọwọ́ agbára mú ìrántí ìṣẹ̀lẹ̀ náà , tí wọ́n sì fi àwọn agbọ̀rọ̀dùn sí àtìmọ́lé . China <organization> |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Lucian Kendel Hippolyte’s pẹ̀lú orin - in ti wọn láti ṣe àrídájú wípé iṣẹ́ náà dé ibi tí ó yẹ kí ó dé . Kendel <person> Hippolyte’s <person> |
|
sentence: Ó sọ wípé òun ti ní ìdojúkọ ìjọba , pẹ̀lú àtìmọ́lé ní ọdún - un 2015 láti dénà dè é kí ó máà lọ sí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ní Geneva . ọdún <location> Geneva <organization> |
|
sentence: Ìfẹ̀sùn Ìbanilórúkọjẹ́ kan Irrawaddy Náà Irrawaddy <person> |
|
sentence: A ò tíì rí nǹkan . |
|
sentence: Bí omi - dídì ilé ayé ṣe ń yọ́ , òkun ń kún . |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Àwọn dókítà méjì kan náà kú látàrí ibà - ẹ̀fọn , èyí sì ti ń mú kí àwọn ènìyàn ó máa bẹ̀rù . |
|
sentence: Ní oṣù Igbe , ìpolówó òkè òkun kan tí ó ní àwòrán Ọkùnrin Ọkọ̀ Ogun fọ́nká sí orí ẹ̀rọ alátagbà orílẹ̀ èdèe China kí a tó mú un wálẹ̀ . oṣù <location> China <organization> |
|
sentence: Nínú oṣùu Ẹrẹ́nà ọdún - un 2019 , a gbé ìgbésẹ̀ kan láti da ilé náà wó lulẹ̀ . oṣùu <location> |
|
sentence: Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn gba ìdájọ́ ìgbà ọdún mẹ́ta ní ẹ̀wọ̀n pẹ̀lú ìdádúró ọdún mẹ́rin sí márùn - ún . ọdún <location> ọdún <location> |
|
sentence: Láìsí àmójútó , ilé yìí ṣì dúró . |
|
sentence: Ọdún - un 2016 ni a ṣe ìgòo ọtí - líle náà , ìyẹn ní ìrántí ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n tí ìṣẹ̀lẹ̀ láabi ọjọ́ 4 oṣù Òkúdù wáyé . Ọdún <location> ọdún <location> ọjọ́ <location> |
|
sentence: Àwọn ọmọ orí ayélujára Àgbáyé , títí kan àwọn tí ó ń lo Reddit , náà ń lo ẹ̀fẹ̀ , ọnà àti àwòrán orí ayélujára tí a fi àyọkà sínúu rẹ̀ rán ni létí nípa ìjàgbara ọ̀rọ̀ ìjọba àwaarawa . Reddit <person> |
|
sentence: Ẹgbẹ́ Olóṣèlú The Communist Party ti China kò fi ìgbà kan sọ ọ́ ní gbangba rí wípé òún mọ̀ wípé ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí ṣẹ̀ tàbí ṣe ìwádìí fínnífínní síwájú sí i . The <person> Communist <organization> Party <organization> ti <organization> China <organization> |
|
sentence: Nínú ọ̀rọ̀ọ rẹ̀ nípa òmìnira ní ọjọ́ 27 , ọdún - un , Alákòóso Ìlú Dókítà . ọjọ́ <location> |
|
sentence: Iléeṣẹ́ náà ti yege nínúu ìtànká àwọn ìkéde tí ó ṣe kókó nípasẹ̀ẹ iṣẹ́ Ohùn fún Àyípadà Ojú - ọjọ́ . |
|
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an |
|
sentence: Òun ni ibùgbé Gómìnà Dhaka ní ayée Ìjọba Mughal . Dhaka <organization> Ìjọba <person> Mughal <organization> |
|
sentence: Mo ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn aláṣẹ fún ogójì ọdún tí ó kọjá láti gba àwọn ilé àjogúnbá bíi Bara Katra àti Choto Katra sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tí ó fẹ́ pa ìtàn àtẹ̀yìnwá rẹ́ . ogójì <location> Bara <organization> Katra <location> Choto <organization> Katra <location> |
|
sentence: Àwọn àjọ àgbáyé ti dẹ̀yìn kọ Òfin Ìṣíkúrò tí ó pàṣẹ àfilé ìdíyelé tí ó gbéra nílẹ̀ fìrì tí ó sì lọ òkè lálá . |
|
sentence: Wọ́n tú yàráa Deng Chuabin wò fún bíi wákàtí kan , wọ́n sì gbé ẹ̀rọ 20 àti agbaná sí ara ẹ̀rọ . Chuabin <person> |
|
|