|
sentence: Àjọ Alágbèélébùú Pupa ní yóò tó ọmọ orílẹ̀ 2 , 700 tí wọ́n pa , àmọ́ àwọn mìíràn nípé ó jù bẹ́ẹ̀ lọ . Àjọ <person> Alágbèélébùú <organization> Pupa <organization> |
|
sentence: Irrawaddy Náà sọ wípé òun kò ṣe àṣemáṣe ju jíjábọ̀ọ ìwọ̀yáàjà tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní sàkání náà láti ìbẹ̀rẹ̀ ọdún - un 2019 . Irrawaddy <person> ọdún <location> |
|
sentence: China fi ọwọ́ọ ṣìnkún òfin mú ayàwòrán eré orí ìtàgé nítorí pé ó tún àwòrán ìgò ọtí - líle kan tí ó ń tọ́ka sí Ìpanìyànnípakúpa Tiananmen pín China <organization> Tiananmen <organization> |
|
sentence: Zeyar Lwin ń tọ́ka sí ìwé òfin ọdún - un 2008 tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn atúnǹkanká gbàgbọ́ wípé a ṣe é to láti fi agbára fún ìṣèjọba ikọ̀ ajagun pàápàá lẹ́yìn tí alágbáda gba ìjọba . Lwin <person> ọdún <location> |
|
sentence: Ragib Hassan ni ó ní àwòrán ní oríi Wikipedia . Hassan <person> Wikipedia <person> |
|
sentence: Àwọn àjogúnbá tí ó gbèèrú àti tí ó ní ìmúgbòrò ti di gbẹndẹ́kẹ : A ò kí ń ṣe òǹrorò , a ò kí ń ṣe oníjàgídíjàgan , a ò kí ń ṣe apanijẹ , a ò kàn kí ń ṣe ọ̀daràn àti ọmọ - ìta . |
|
sentence: Ó jẹ́ nǹkan ìbànújẹ́ wípé ilé náà ti ṣe tán , ó lè wó nígbàkigbà látorí àìṣàtúnṣe , àìkáràmáìsìkí ohun àjogúnbá , àti ìbàjẹ́ tí àwọn tí ó gbé ilé láì gba àṣẹ ń fà . |
|
sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Simão Rossi , a lò ó pẹ̀lú àṣẹ . Rossi <person> |
|
sentence: Nínú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ iṣẹ́ ìkọ̀ròyìn ni ó ti fi lélẹ̀ wípé a gbọdọ̀ tànmọ́lẹ̀ sí ìjìyà àwọn ènìyàn ní ibi tí rògbòdìyàn bá wà . |
|
sentence: Ìròyìn fi yé wípé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó wà lórí ipò ìyẹn Awami League ( AL ) gbé ẹ̀rọ tatapùpù wá sí ibẹ̀ , wọ́n sì da ilé náà wó . |
|
sentence: Ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí ó dá mi lóhùn . |
|
sentence: Àwọn òǹlò ẹ̀rọ - alátagbà sọ ti wọn . |
|
sentence: Ka àwọn ọ̀ràn ìsàlẹ̀ yìí síwájú : |
|
sentence: Nígbà tí ẹ̀ka tí ó ń ṣe àkópamọ́ sítám̀pù ti wo ògiri àtijọ́ àmọ̀káyée Lalbagh Fort láti fi ṣe àyè ìgbọ́kọ̀sí , báwo ni a ó ṣe dojú ìjà kọ ìwà òmùgọ̀ ? Lalbagh <organization> Fort <location> |
|
sentence: A fi ọwọ́ọ ṣìnkún òfin mú àwọn ọmọkùnrin orílẹ̀ èdèe China mẹ́rin , Fu Hailu , Zhang Jinyong , Luo Fuyu àti Chen Bing , ní ọdún - un 2016 fún ìṣẹ̀lẹ̀ ìgò ọtí - líle tí a sì fi ẹ̀sùn - un “ rírú ìṣẹ́po agbáraiìlú sókè """" . China <organization> Hailu <person> Jinyong <person> Fuyu <person> Bing <person> ọdún <location> |
|
sentence: Northbrook Hall . Northbrook <organization> Hall <location> |
|
sentence: Àjọṣepọ̀ tí ó dán mọ́nrán ń bẹ ní àárín - in Ohùn Àgbáyé àti Irrawaddy . Ohùn <person> Àgbáyé <organization> Irrawaddy <person> |
|
sentence: Orúkọ tí a pe ọtí - líle náà ni “ 8 wine 64 ″ . |
|
sentence: Níbẹ̀ , ọ̀kọrin ọmọ Jamaica Aaron Silk darapọ̀ mọ́ àwọn olórin mìíràn — pẹ̀lú eléré Belizean Adrian Martinez — láti ṣe alágbàáwí ìdínkù fún ìgbóná àgbáyé sí ìwọ̀n - ọn ojúàmì 1 . 5 . Jamaica <organization> Silk <person> Adrian <person> Martinez <person> |
|
sentence: Ọdún - un 1610 ni Dhaka di olú - ìlúu Bengal , ìyẹn ogójì ọdún sẹ́yìn . Ọdún <location> Dhaka <organization> Bengal <organization> ogójì <location> |
|
sentence: Àmì ibà - ẹ̀fọn àti àtiṣe . . |
|
sentence: Àjùsẹ́wọ̀n fún yẹ̀yẹ́ |
|
sentence: Àwòrán àti ọ̀rọ̀ abẹ́ - àwòrán láti ọwọ́ọ Myo Min Soe / Irrawaddy náà ń bá Ohùn Àgbáyé ṣiṣẹ́ ìròyìn . Min <person> Soe <person> Irrawaddy <person> Ohùn <person> Àgbáyé <organization> |
|
sentence: Èyí jẹ́ ìrántí ohun tí ojú àwọn ọmọ Mozambique rí ní ìparí ọdún - un 2018 , nígbàtí ìjọba pinnu láti fi owó kún ìwé àṣẹ gbogbo , bẹ́ẹ̀ náà ni ó bá ìwé àṣẹ ọkọ̀ wíwà , tí ìdíyelée rẹ̀ fi ìdá 500 gbéwó lórí . Mozambique <organization> ìparí <location> |
|
sentence: Olórí ni wa , aronújinlẹ̀ ni wa , ọlọ́pọlọ pípé ni wa , onímọ̀ ni wa . |
|
sentence: Hannan Gazi náà se àgbéjáde tirẹ̀ : Gazi <person> |
|
sentence: Wọ́n gba ẹ̀sìn àwọn babańláa wa , wọ́n mú ìgbàgbọ́ àti ohun iyìi wa kúrò ní ọkàn - an wa . |
|
sentence: Àdàwólulẹ̀ tí a da ilé yìí ti mú kí àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn ó sọ ẹ̀dùn ọkàn - an wọn síta lórí àìbìkítà fún àwọn ilé tí ó jẹ́ ohun ìṣúra Dhaka . Dhaka <organization> |
|
sentence: Àwọn ẹgbẹ́ iléeṣẹ́ oníròyìn àti ajà - fún - ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ń ṣe àjọyọ̀ọ ti ìdásílẹ̀ lẹ́wọ̀n - ọn akọ̀ròyìn Reuters Wa Lone àti Kyaw Soe Oo tí ó lò ju ọjọ́ 500 ní àtìmọ́lé fún ipa tí wọ́n kó nínú ìwádìí òfíntótó ìṣẹ̀lẹ̀ ìpanípakúpa àwọn olùgbée Rohingya kan ní gúúsù Myanmar . Reuters <person> Lone <person> Soe <person> Oo <person> Rohingya <organization> gúúsù <organization> Myanmar <location> |
|
sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Fernando Gomes , a gba àṣẹ láti lò ó . Gomes <person> |
|
sentence: A máa wà ní ojú òpópónà ní olú ìlú fún oṣù Èrèlé , ní àwọn ọjọ́ kọ̀ọ̀kan tí a yàn , ọjọ́ kẹrin oṣù Èrèlé ni ìwọ́de náà bẹ̀rẹ̀ , àmọ́ ní ọjọ́ kéje ni a máa padà sí ojú òpópónà , tí a óò tún wà ní ọjọ́ kankànlá , tí a ó sì jábọ̀ ní ọjọ́ kẹtàlá , bí ìjọba kò bá yí ohùn padà . oṣù <location> ọjọ́ <location> ọjọ́ <location> ọjọ́ <location> ọjọ́ <location> |
|
sentence: Àwọn tó bá ara wọn ní ìsàlẹ̀ ní ìṣòro láti bá àwọn tí ó wà ní òkè ṣe . |
|
|