File size: 5,920 Bytes
868d802
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
sentence: Ní Taiwan , àgbékalẹ̀ẹ ọnà alágbára kan tí a gbé sí àárín gbùngbùn Taipei ń ṣe ìrántí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ọdún - un 1989 .	Taiwan <organization> àárín <organization> gbùngbùn <location> Taipei <location> ọdún <location>
sentence: Ilé oníròyìn orí - ayélujára kan ti ṣe àtẹ̀jáde àbájáde ìwádìí tí ó jinlẹ̀ nípa àìkáràmáìsìkí ìjọba lóríi àwọn ilé àjogúnbá àti àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ tí ó ń gbìyànjú láti da àwọn ilé tí ó kù wó :	
sentence: Àtẹ̀jáde ìtúmọ̀ 8 Òkúdù 2019 22 : 44 GMT	8 <location>
sentence: a ti ṣe ń pe “ wine """" ní èdèe Putonghua náà ni à ń pe “ 9 """" .	
sentence: Ìyẹn bẹ́ẹ̀ , àwọn ọmọ ẹgbẹ́ẹ ajótà Ìran Ọ̀kín Thangya márùn - ún di èrò ẹ̀wọ̀n tí ó wà ní Insein títí di ìgbà tí wọn yóò lọ sí ilé ẹjọ́ fún ẹ̀fẹ̀ tí wọ́n fi ológun ṣe .	Ìran <person> Ọ̀kín <organization> Thangya <organization> Insein <organization>
sentence: Muntasir Mamun ti kọ àìmọye ìwé lóríi ìtàn - ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìnwá àti àjogúnbá ìlúu Dhaka .	Mamun <person> Dhaka <organization>
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an	
sentence: Iléeṣẹ́ náà ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìpolongo ìkéde àyípadà ojú - ọjọ́ ní agbègbè mẹ́rin ní àárín - in Jamaica : Rocky Point àti Lionel Town ní ẹ̀ka ìlúu Clarendon , Ridge Red Bank ní St .	Jamaica <organization> Rocky <organization> Point <location> Lionel <organization> Town <location> Clarendon <organization> Ridge <organization> Red <location> Bank <location>
sentence: Ìgò ọtí - líle 64	
sentence: Ní ọdún yìí ni a sààmì ọgbọ̀n ọdún ohun tí ó fa sábàbí ìpaninípakúpa ọjọ́ 4 oṣù Òkúdù àti láti ṣe ojúṣe wa láti rán àwọn ènìyàn létí , pẹ̀lú gbogbo ọ̀nà àgàbàgebè Beijing ń gbà láti fi eérú bo òtítọ́ mọ́lẹ̀ .	ọdún <location> ọgbọ̀n <location> ọjọ́ <location> Beijing <organization>
sentence: Gẹ́gẹ́ àwọn onímọ̀ kan ṣe rò , ipa ìyípadà ojú - ọjọ́ , òàìdágbá kan , ojú - ọjọ́ tó ń ṣe ségesège , àti àìṣèmọ́tótó ni ọ̀dádá tí ó ń dá àtànkálẹ̀ ibà sílẹ̀ .	
sentence: A lò ó pẹlú àṣẹ .	
sentence: Ajábọ̀ - ìròyín Arthur Dash gbóríyìn fún “ ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìnwá ìdàgbàsókè """" orílẹ̀ - èdè náà ní ti ọ̀ràn - an ẹ̀yà , àmọ́ ó tún dá àwípé ìṣòro náà ju àwọn ti ṣe rò lọ , ó sì mú u ní àpé ó yẹ kí ọ̀rọ̀ alákòóso ìlú jẹ́ ìwúrí fún ọmọìlú láti ṣe ìwádìí fínnífínní sí Dash <person>
sentence: Àkọsílẹ̀ Àìsàn Pọ̀ Sí i Ní Osù Agẹmọ	Osù <location>
sentence: Olùyàwòrán agbègbè Sammy Junior , láti Rocky Point , Clarendon ( agbègbè tí ìrúsókè - odò ọ̀sà àti àgbàrá ibi tí ó súnmọ́ omi ti kó ) níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tí ó dá lóríi Ìfiṣẹ́ránṣẹ́ Àyípadà Ojú - ọjọ́ Jamaica ní ọjọ́ 14 oṣù Ẹrẹ́nà , ọdún - un 2019 .	Junior <person> Rocky <organization> Point <location> Clarendon <organization> Jamaica <organization> jọ́ <location>
sentence:jẹ́ ká mọ̀ wípé ìyàsọ́tọ̀ọ̀tọ̀ nípa ti àwọ̀ ara ni ogún tí ó ń pín wa níyà [ … ]	
sentence: Ẹgbẹ́ Olóṣèlú The Communist Party ti China kò fi ìgbà kan sọ ọ́ ní gbangba rí wípé òún mọ̀ wípé ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí ṣẹ̀ tàṣe ìwádìí fínnífínní síwásí i .	The <person> Communist <organization> Party <organization> ti <organization> China <organization>
sentence: Àwọn tí ó ń kú nh pọ̀ ọ́ sí i .	
sentence: Àwòrán àti ọ̀rọ̀ abẹ́ - àwòrán láti ọwọ́ọ Myo Min Soe / Irrawaddy náà ń Ohùn Àgbáyé ṣiṣẹ́ ìròyìn .	Min <person> Soe <person> Irrawaddy <person> Ohùn <person> Àgbáyé <organization>
sentence: Àwọn tí ó wá ṣiṣẹ́ náà sọ wípé olóríi àwọn , ọmọ ìgbìmọ̀ ìbílẹ̀ ( Dhaka - 7 ) Haji Md .	Dhaka <organization> Md <person>
sentence: Bara Katra .	Katra <person>
sentence: Mo ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn aláṣẹ fún ogóọdún tí ó kọláti gba àwọn ilé àjogúnbá bíi Bara Katra àti Choto Katra sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tí ó fẹ́ pa ìtàn àtẹ̀yìnwá rẹ́ .	ogó<location> Bara <organization> Katra <location> Choto <organization> Katra <location>
sentence: Ìyá Ilẹ̀ - ayé ń ké tantan	
sentence: Wo òkúta ìsàlẹ̀ òkun , wo ẹja ó ṣe kéré	
sentence: Ìfọwọ́ọ ṣìnkún òfin múni nítorí àtúnpín túwíìtì	
sentence: Èyí kò rí ajàfẹ́tọ̀ọ́ AL náà ti ṣe wí , kò sí ohun tó jọ ọ́ , kò sí àṣẹ tí ó ní kí wọ́n tà tàwó ilé tí à ń sọ̀rọ̀ọ rẹ̀ yìí .	
sentence: Nínú igbó kìjikìji bi tí àwọn igi ń wó sí	
sentence: Àkọpamọ́ kan tí ó jẹ́ ti ìjọba US jábọ̀ ní ọdún - un 2014 wípé àyẹ̀wò tí ó wáyé nínú China sọ wípé yóò fẹ́rẹ̀ẹ́ tó ọmọ orílẹ̀ 10 , 454 tí wọ́n pa .	ìjọba <person> US <organization> ọdún <location> China <organization>
sentence: Ó ká mi lára nípé iṣẹ́ẹ wa kò yé ikọ̀ ajagun yékéyéké .	
sentence: Ère Orin Ìràpadà , Ọgbà Òmìnira , Jamaica .	Jamaica <organization>
sentence: Òmìnira yìí faramọ́ ẹni tí o jẹ́ , ibi tí o ti ṣẹ̀ wá , ẹ̀jẹ̀ àti ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìwá tí ó wà nínú iṣan - ẹ̀jẹ̀ .	
sentence: Àtẹ̀jáde ìtúmọ̀ 22 Èbìbì 2019 13 : 12 GMT	22 <location>