sentence: Ní Taiwan , àgbékalẹ̀ẹ ọnà alágbára kan tí a gbé sí àárín gbùngbùn Taipei ń ṣe ìrántí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ọdún - un 1989 . Taiwan àárín gbùngbùn Taipei ọdún sentence: Ilé oníròyìn orí - ayélujára kan ti ṣe àtẹ̀jáde àbájáde ìwádìí tí ó jinlẹ̀ nípa àìkáràmáìsìkí ìjọba lóríi àwọn ilé àjogúnbá àti àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ tí ó ń gbìyànjú láti da àwọn ilé tí ó kù wó : sentence: Àtẹ̀jáde ìtúmọ̀ 8 Òkúdù 2019 22 : 44 GMT 8 sentence: Bí a ti ṣe ń pe “ wine """" ní èdèe Putonghua náà ni à ń pe “ 9 """" . sentence: Ìyẹn bẹ́ẹ̀ , àwọn ọmọ ẹgbẹ́ẹ ajótà Ìran Ọ̀kín Thangya márùn - ún di èrò ẹ̀wọ̀n tí ó wà ní Insein títí di ìgbà tí wọn yóò lọ sí ilé ẹjọ́ fún ẹ̀fẹ̀ tí wọ́n fi ológun ṣe . Ìran Ọ̀kín Thangya Insein sentence: Muntasir Mamun ti kọ àìmọye ìwé lóríi ìtàn - ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìnwá àti àjogúnbá ìlúu Dhaka . Mamun Dhaka sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an sentence: Iléeṣẹ́ náà ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìpolongo ìkéde àyípadà ojú - ọjọ́ ní agbègbè mẹ́rin ní àárín - in Jamaica : Rocky Point àti Lionel Town ní ẹ̀ka ìlúu Clarendon , Ridge Red Bank ní St . Jamaica Rocky Point Lionel Town Clarendon Ridge Red Bank sentence: Ìgò ọtí - líle 64 sentence: Ní ọdún yìí ni a sààmì ọgbọ̀n ọdún ohun tí ó fa sábàbí ìpaninípakúpa ọjọ́ 4 oṣù Òkúdù àti láti ṣe ojúṣe wa láti rán àwọn ènìyàn létí , pẹ̀lú gbogbo ọ̀nà àgàbàgebè tí Beijing ń gbà láti fi eérú bo òtítọ́ mọ́lẹ̀ . ọdún ọgbọ̀n ọjọ́ Beijing sentence: Gẹ́gẹ́ bí àwọn onímọ̀ kan ṣe rò , ipa ìyípadà ojú - ọjọ́ , òjò àìdágbá kan , ojú - ọjọ́ tó ń ṣe ségesège , àti àìṣèmọ́tótó ni ọ̀dádá tí ó ń dá àtànkálẹ̀ ibà sílẹ̀ . sentence: A lò ó pẹlú àṣẹ . sentence: Ajábọ̀ - ìròyín Arthur Dash gbóríyìn fún “ ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìnwá ìdàgbàsókè """" orílẹ̀ - èdè náà ní ti ọ̀ràn - an ẹ̀yà , àmọ́ ó tún dá àbá wípé ìṣòro náà ju bí àwọn ti ṣe rò lọ , ó sì mú u ní àbá pé ó yẹ kí ọ̀rọ̀ alákòóso ìlú jẹ́ ìwúrí fún ọmọìlú láti ṣe ìwádìí fínnífínní sí bí Dash sentence: Àkọsílẹ̀ Àìsàn Pọ̀ Sí i Ní Osù Agẹmọ Osù sentence: Olùyàwòrán agbègbè Sammy Junior , láti Rocky Point , Clarendon ( agbègbè tí ìrúsókè - odò ọ̀sà àti àgbàrá ibi tí ó súnmọ́ omi ti kó bá ) níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tí ó dá lóríi Ìfiṣẹ́ránṣẹ́ Àyípadà Ojú - ọjọ́ ní Jamaica ní ọjọ́ 14 oṣù Ẹrẹ́nà , ọdún - un 2019 . Junior Rocky Point Clarendon Jamaica ọjọ́ sentence: Ẹ jẹ́ ká mọ̀ wípé ìyàsọ́tọ̀ọ̀tọ̀ nípa ti àwọ̀ ara ni ogún tí ó ń pín wa níyà [ … ] sentence: Ẹgbẹ́ Olóṣèlú The Communist Party ti China kò fi ìgbà kan sọ ọ́ ní gbangba rí wípé òún mọ̀ wípé ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí ṣẹ̀ tàbí ṣe ìwádìí fínnífínní síwájú sí i . The Communist Party ti China sentence: Àwọn tí ó ń kú nh pọ̀ ọ́ sí i . sentence: Àwòrán àti ọ̀rọ̀ abẹ́ - àwòrán láti ọwọ́ọ Myo Min Soe / Irrawaddy náà ń bá Ohùn Àgbáyé ṣiṣẹ́ ìròyìn . Min Soe Irrawaddy Ohùn Àgbáyé sentence: Àwọn tí ó wá ṣiṣẹ́ náà sọ wípé olóríi àwọn , ọmọ ìgbìmọ̀ ìbílẹ̀ ( Dhaka - 7 ) Haji Md . Dhaka Md sentence: Bara Katra . Katra sentence: Mo ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn aláṣẹ fún ogójì ọdún tí ó kọjá láti gba àwọn ilé àjogúnbá bíi Bara Katra àti Choto Katra sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tí ó fẹ́ pa ìtàn àtẹ̀yìnwá rẹ́ . ogójì Bara Katra Choto Katra sentence: Ìyá Ilẹ̀ - ayé ń ké tantan sentence: Wo òkúta ìsàlẹ̀ òkun , wo ẹja bí ó ṣe kéré sentence: Ìfọwọ́ọ ṣìnkún òfin múni nítorí àtúnpín túwíìtì sentence: Èyí kò rí bí ajàfẹ́tọ̀ọ́ AL náà ti ṣe wí , kò sí ohun tó jọ ọ́ , kò sí àṣẹ tí ó ní kí wọ́n tà tàbí wó ilé tí à ń sọ̀rọ̀ọ rẹ̀ yìí . sentence: Nínú igbó kìjikìji níbi tí àwọn igi ń wó sí sentence: Àkọpamọ́ kan tí ó jẹ́ ti ìjọba US jábọ̀ ní ọdún - un 2014 wípé àyẹ̀wò tí ó wáyé nínú China sọ wípé yóò fẹ́rẹ̀ẹ́ tó ọmọ orílẹ̀ 10 , 454 tí wọ́n pa . ìjọba US ọdún China sentence: Ó ká mi lára nípé iṣẹ́ẹ wa kò yé ikọ̀ ajagun yékéyéké . sentence: Ère Orin Ìràpadà , Ọgbà Òmìnira , Jamaica . Jamaica sentence: Òmìnira yìí faramọ́ ẹni tí o jẹ́ , ibi tí o ti ṣẹ̀ wá , ẹ̀jẹ̀ àti ìṣẹ̀lẹ̀ - àtẹ̀yìwá tí ó wà nínú iṣan - ẹ̀jẹ̀ . sentence: Àtẹ̀jáde ìtúmọ̀ 22 Èbìbì 2019 13 : 12 GMT 22